“Elíjà àti Ohùn Jẹ́jẹ́, Kékeré náà” Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì , Oṣù Keje 2022
“Elíjà àti Ohùn Jẹ́jẹ́, Kékeré náà”
Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì, Oṣù Kéje 2022
Elíjà àti Ohùn Jẹ́jẹ́, Kékeré náà
Ábráhámù jẹ́ wòlíì nlá kan. Ó fẹ́ gbọ́ ohun Ọlọ́run. Ó lọ sí orí òkè kan láti gbọ́ ohùn Ọlọ́run dáradára.
Ìjì líle kan wà. Ó le tó bẹ́ẹ̀ tí ó fọ́ àwọn àpáta. Ìjì náà jẹ́ aláriwo. Ṣùgbọ́n kìí ṣe ohùn Ọlọ́run.
Ní títẹ̀lé ilẹ̀ ríri kan wà. Ilẹ̀ ayé mì tìtì. Iná kan wà níbẹ̀ pẹ̀lú. O ní àwọn iná nlá. Ṣùgbọ́n ilẹ̀ ríri àti iná náà kìí ṣe ohùn Ọlọ́run.
Nígbànáà ìdákẹ́rọ́rọ́ wà Elíjà gbọ́ ohùn Ọlọ́run Ó jẹ́ jẹ́jẹ́ àti kékeré Ṣùgbọ́n ó ṣe kedere.
Mo le gbọ́ ohùn Ọlọ́run nípa fífi etí sílẹ̀ sí Ẹmí Mímọ́. Ó nbá mi sọ̀rọ̀ ní àwọn ò̩nà kékeré tí ó sì rọrùn.
© 2022 láti ọwọ́ Intellectual Reserve, Inc. Gbogbo àwọn ẹ̀tọ́ ni a fipamọ́. A tẹ̀ẹ́ ní USA. Àṣẹ Èdè Gẹẹsì: 6/19. Àṣẹ Ìyírọ̀padà-èdè: 6/19. Ìyírọ̀padà-èdè ti Ọ̀rọ̀ Fríẹ́ndì Oṣooṣù, Oṣù Kéje 2022. Yoruba 18298 779