“Iṣẹ́-ìyanu Tabitha,” Fríẹ́ndì, Oṣù Kẹsan 2023, 46–47.
Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ̀ndì, Oṣù Kẹsan 2023
Iṣẹ́-ìyanu Tabitha
Tàbíthà jẹ́ àtẹ̀lé Jésù Krístì Ó rán àwọn aṣọ àti kóòtù ó sì ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ohun rere fún àwọn ẹlòmíràn.
Ṣùgbọ́n nígbànáà Tàbíthà ṣe àárẹ̀ ó sì kú. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn banújẹ́.
Wòlíì, Pétérù, lọ sọ́dọ̀ Tàbíthà. Ó jí i dìde kúrò nínú òkú pẹ̀lú agbára tí Jésù Krístì fún un.
Tàbíthà wà láàyè lẹ́ẹ̀kansi! Òun lè ránṣọ́ ó sì lè sìn bákannáà lẹ́ẹ̀kansì. Ó jẹ́ iṣẹ́-ìyanu kan.
© 2023 nípasẹ̀ Intellectual Reserve, Inc. Gbogbo ẹ̀tọ́ ní a pamọ́. A tẹ̀ẹ́ ní USA. Àṣẹ Èdè Gẹẹsì: 6/19. Àṣẹ Ìyírọ̀padà: 6/19. Ìyírọ̀pada Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì, Oṣù Kẹsan 2023. Language. 19047 779