2023
Àwọn Olùṣọ́-àgùtàn Bẹ Jésù Ọmọ-ọwọ́ Wò
Oṣù Kejìlá 2023


“Àwọn Olùṣọ́-àgùtàn Bẹ Jésù Ọmọ-ọwọ́ Wò,” Fríẹ́ndì Oṣù Kejìlá. 2023, 46–47.

Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì , Oṣù Kejìlá 2023

Àwọn Olùṣọ́-àgùtàn Bẹ Jésù Ọmọ-ọwọ́ Wò

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Àwọn ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Ní òru kan, àngẹ̀lí kan bẹ àwọn olùṣọ́-àgùtàn wò nínú pápá. Ángẹ́lì náà wí fún wọn pé a ti bí ọmọ-ọwọ́ pàtàkì kan. Orúkọ Rẹ̀ ni Jésù Krístì. Òun ó jẹ́ Olùgbàlà fún gbogbo ènìyàn ní ayé. Àwọn ángẹ́lì púpọ̀si wá. Wọ́n kọrin, “Ògo fún Ọlọ́run lóke, àti àláfíà ní aye, ìfẹ́-inú rere sí ènìyàn.”

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Àwọn olùṣọ́-àgùtàn yára lọ bẹ Jésù ọmọ-ọwọ́ wo. Inú wọn dùn gidi láti rí I!

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Àwọn olùṣọ́-àgùtàn wí fún àwọn ẹlòmíràn nípa Jésù Krístì. Wọ́n fẹ́ kí gbogbo ènìyàn gbọ́ ìròhìn rere náà.

Kíkùn Ojú-ewé

Èmi Lè kọrin nípa Jésù Krístì

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà níhin

Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Mo lè kọ àwọn orin nípa Jésù láti ṣe àjọyọ ìbí Rẹ̀.

Tẹ̀