Àwọn Ìrànlọ́wọ́ Àṣàrò
Atọ́ka Ìtọ́ni sí Bíbélì Mímọ́


Atọ́ka Ìtọ́ni sí Bíbélì Mímọ́

Bíbélì ni a pín sí abala méjì: Májẹ̀mú Láéláé àti Májẹ̀mú Titun. Májẹ̀mú Láéláé ni àkọsílẹ̀ mímọ́ nípa àwọn ìbáṣe Ọlọ́run pẹ̀lú àwọn ènìyàn májẹ̀mú Rẹ̀ nínú Ilẹ́ Mímọ́. Ó ní àwọn ìkọ́ni ti irú àwọn wòlíì bí Mósè, Joshua, Isaiah, Jeremiah, àti Daniel nínú. Májẹ̀mú Titun ṣe àwọn akọsílẹ̀ ìbí, iṣẹ́-ìránṣẹ́ ayé-ikú, Ètùtù, àti Àjínde Olùgbàlà. Ó parí pẹ̀lú iṣẹ́-ìránṣẹ́ ti àwọn Àpọ́sélì Olùgbàlà.

Ìtọ́ni yí pèsè àwọn atọ́ka ti Bíbélì rírannilọ́wọ́ tí a pín sí abẹ́ àwọn àkórí wọ̀nyí:

  • Olórí-ọ̀run

  • Àwọn Àkòrí Ìhìnrere

  • Àwọn Ènìyàn

  • Àwọn ibi

  • Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀

Fún àfikún àwọn ìrànlọ́wọ́ àṣàrò, wo Ìtọ́ni sí àwọn Ìwé-mímọ́, tí a tẹ̀ jáde pẹ̀lú Iwé ti Mọ́mọ́nì, Ẹ̀kọ́ àti àwọn Májẹ̀mú, àti Píálì Olówó Iyebíye.

Àjọ Olórí-ọ̀run

Àwọn Àkòrí Ìhìnrere

Àwọn Ènìyàn

Àwọn ibìkan

Bákannáà wo àwọn mápù àti àwòrán tí ó tẹ̀lé atọ́ka ìtọ́ni Bíbélì.

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀