2021
A Bí Jésù
Oṣù Kejìlá 2021


“A Bí Jésù,” Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì, Oṣù Kejìlá 2021, 2019

“A Bí Jésù”

Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì, Oṣù Kejìlá 2021

A Bí Jésù

Lúkù 2:1-20.

Àwòrán
Jésù ọmọ ọwọ́, Màríà, àti Jósẹ́fù

Ní àkókò Kérésìmesì, a nṣe àjọyọ̀ ìbí ti Jésù Krístì.

Àwòrán
Màríà àti Jósẹ́fù ngbà Jésù ọmọ-ọwọ́ mọ́ àyà

A Bí Jésù ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù Ìyá rẹ̀ ní a pè ní Màríà, Jósẹ́fù sì ni ọkọ rẹ̀.

Àwòrán
Símónì ngbé Jésù ọmọ-ọwọ́ dání

Màríà àti Jósẹ́fù mú Jésù ọmọ-ọwọ́ lọ sí tẹ́mpìlì ní Jérúsálẹ́mù. Níbẹ̀, ọkùnrin kan tí a pè ní Símónì gbé Jésù ọmọ-ọwọ́. Ó ní ìmọ̀lára Ẹ̀mí Mímọ́ tí ó nsọ fún un pé Jésù ni Ọmọ Ọlọ́run náà.

Àwòrán
Annà nkéde sí àwọn èrò

Obìnrin kan tí a pè ní Annà rí Jésù ọmọ-ọwọ́ bákanná ó sì mọ̀ pé Òun ni Olùgbàlà náà. Ó lọ láti sọ fún àwọn ènìyàn míràn nípa Rẹ̀.

Àwòrán
Ọmọdé ngbé àtùpà dání

Mo máa nronú nípa Jésù ní àkókò Kérésìmesì. Ó wá láàyè nítòótọ́. Ó fẹ́ràn mi!

Ojú-ewé Kíkùn

Ọdún Kérésìmesì jẹ́ nípa Jésù

Àwòrán
Màríà àti Jósẹ́fù gbé Jésù ọmọ-ọwọ́ dání

Tẹ̀ àwòrán náà láti ṣe ìgbàsílẹ̀.

Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Tẹ̀