2022
Ṣíwájú Kí A Tó Wá sí Ilẹ̀-ayé
Oṣù Kínní 2022


“Ṣíwájú Kí A Tó Wá sí Ilẹ̀-ayé,” Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì , Oṣù Ìkínní 2022

“Ṣíwájú Kí A Tó Wá sí Ilẹ̀-ayé”

Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì , Oṣù Ìkínní 2022

Ṣíwájú Kí A Tó Wá sí Ilẹ̀-ayé

Àwòrán
Baba Ọ̀run àti Jésù Krístì ní ìṣaájú ayé ẹ̀mí

Àwọn Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Ṣíwájú kí a tó bí wa, a gbé ní ọ̀run pẹ̀lú Baba Ọ̀run. Ó kọ́ wa nípa ètò ìdùnnú Rẹ̀.

Àwòrán
ọmọdékùnrin nsọkún, ọmọdébìnrin pẹ̀lú bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá

Baba Ọ̀run wípé a ó wá sí ilẹ̀-ayé láti gba àwọn ara. A ó kẹkọ a ó sì ṣe àṣàyàn. Nígbàmíràn a ó ṣe àwọn àṣìṣe. A ó nílò Olùgbàlà kan.

Àwòrán
ọmọdébìnrin pẹ̀lú bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá tí ó ntu ọmọdébìnrin tí ó nsọkún nínú

Olùgbàlà yíò fihàn wá bí a ó ṣe gbé ìgbé-ayé. Àti nígbàtí a bá ṣe àṣàyàn ìṣìṣe, a ó lè ronúpíwàdà.

Àwòrán
Jésù Krístì Ìṣaájú-ayé

Jésù wípé, “Èmi nìyí, rán mi.” Baba Ọ̀run yàn Án láti jẹ́ Olùgbàlà wa. Jésù Ṣe ìlérí láti wá sí ilẹ̀-ayé láti gbà wá là.

Àwòrán
Baba Ọ̀run àti Jésù Krístì ní ìjọba sẹ̀lẹ́stíà

Mo lè tẹ̀lé Jésù Níjọ́kan mo lè padà kí n sì gbe pẹ̀lú Baba Ọ̀run.

Ojú-ewé Kíkùn

Èmi Jẹ́ Ọmọ Ọlọ́run

Àwòrán
Àwọn ọmọdé nwo àwọn ìràwọ̀

Tẹ̀ àwòrán náà láti ṣe ìgbàsílẹ̀.

Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Báwo ni ẹ ṣe nní ìmọ̀lára ìfẹ́ Baba Ọ̀run?

Tẹ̀