“Àwọn Ẹ̀bun fún Jésù,” Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì , Oṣù Kínní 2023
“Àwọn Ẹ̀bun Fún Jésù”
Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì , Oṣù Kínní 2023
Àwọn Ẹ̀bun Fún Jésù
Nígbàtí a bí Jésù Krístì, ìràwọ̀ titun kan jáde ní ojú ọ̀run. Àwọn Amòye mọ̀ pé ìràwọ̀ túmọ̀ sí pé a ti bí Jésù. Wọ́n tẹ̀lé ìràwọ̀ náà. Wọ́n rin ìrìnàjò fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́.
Nígbàtí Àwọn Amòye rí Jésù, wọ́n fun Un ní àwọn ẹ̀bùn. Wọ́n kúnlẹ̀ níwájú Rẹ̀, wọ́n fún Un ní àwọn ẹ̀bùn. Wọ́n mọ̀ pé Òun ni Ọmọ Ọlọ́run.
Mo lè fi ẹ̀bùn fún Jésù pẹ̀lú. Mo lè fi ìfẹ́ mi hàn fún Un nígbàtí mo bá tẹ̀lé àpẹrẹ Rẹ̀ tí mo sì fi ìfẹ́ hàn sí àwọn ẹlòmíràn.
© 2023 nípasẹ̀ Intellectual Reserve, Inc. Gbogbo àwọn ẹ̀tọ́ ni a fipamọ́. A tẹ̀ẹ́ ní USA. Àṣẹ Èdè Gẹẹsì: 6/19. Àṣẹ Ìyírọ̀padà-èdè: 6/19. Ìyírọ̀padà-èdè ti Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì, Oṣù Kínní 2023. Language. 18904 779