2023
Àwọn Ẹ̀bun Fún Jésù
Oṣù Kínní 2023


“Àwọn Ẹ̀bun fún Jésù,” Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì , Oṣù Kínní 2023

“Àwọn Ẹ̀bun Fún Jésù”

Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì , Oṣù Kínní 2023

Àwọn Ẹ̀bun Fún Jésù

Àwòrán
Màríà pẹ̀lú Jésù ọmọ-ọwọ́

Àwọn Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Àwòrán
Àwọn Amòye nrin ìrìnàjò

Nígbàtí a bí Jésù Krístì, ìràwọ̀ titun kan jáde ní ojú ọ̀run. Àwọn Amòye mọ̀ pé ìràwọ̀ túmọ̀ sí pé a ti bí Jésù. Wọ́n tẹ̀lé ìràwọ̀ náà. Wọ́n rin ìrìnàjò fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́.

Àwòrán
Àwọn Amòye

Nígbàtí Àwọn Amòye rí Jésù, wọ́n fun Un ní àwọn ẹ̀bùn. Wọ́n kúnlẹ̀ níwájú Rẹ̀, wọ́n fún Un ní àwọn ẹ̀bùn. Wọ́n mọ̀ pé Òun ni Ọmọ Ọlọ́run.

Àwòrán
àwọn ọmọdé ngbá yìnyìn

Mo lè fi ẹ̀bùn fún Jésù pẹ̀lú. Mo lè fi ìfẹ́ mi hàn fún Un nígbàtí mo bá tẹ̀lé àpẹrẹ Rẹ̀ tí mo sì fi ìfẹ́ hàn sí àwọn ẹlòmíràn.

Kíkùn Ojú-ewé

Bíbélì Nkọ́ni nípa Jésù

Àwòrán
baba àti ọmọbìnrin nka àwọn ìwé mímọ́

Tẹ̀ àwòrán náà láti ṣe ìgbàsílẹ̀.

Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Báwo ni ẹ ṣe ntiraka láti dàbí ti Jésù sí?

Tẹ̀