2023
Wòlíì Pétérù
Oṣù Keje 2023


“Wòlíì Pétérù,” Fríẹ̀ndì, Oṣù Kéje 2023, 46–47.

Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì, Oṣù Kéje 2023

Wòlíì Pétérù

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Àwọn ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Lẹ́hìn tí Jésù Krístì jínde tí ó sì lọ sí ọ̀run, Pétérù di wòlíì.

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Pétérù kọ́ àwọn ènìyàn nípa ìrìbọmi àti Ẹ̀mí Mímọ́. Ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ènìyàn yàn láti ṣe ìrìbọmi!

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Ní ọjọ́ kan Pétérù rí ọkùnrin kan ní ìta tẹ́mpìlì. Ọkùnrin náà kò lè rìn. Pétérù wí pé, “Ní orúkọ Jésù Krístì, dìde kí o sì máa rìn.”

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Ọkùnrin náà ni a wòsàn nítorí ìgbàgbọ́ rẹ̀! Pétérù kọ́ àwọn ènìyàn ní tẹ́mpìlì nípa Jésù Krístì.

Kíkùn Ojú-ewé

Mo Lè Sọ Fún Àwọn Ẹlòmíràn nípa Jésù

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Tẹ̀