“Páùlù Kọ́ Wa láti Tẹ̀lé Jésù Krístì,” Fríẹ́ndì, Oṣù Kẹwa 2023, 46–47.
Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Làìhónà, Oṣù Kẹwa 2023
Páùlù Kọ́ Wa láti Tẹ̀lé Jésù Krístì
Àwọn ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott
Páùlù jẹ́ Àpóstélì kan. Ó kọ́ wa láti jẹ́ àpẹrẹ sí àwọn ẹlòmíràn. Èyí túmọ̀sí ṣíṣe ohun tí Jésù Krístì yíò ṣe.
Páùlù wípé a nílátì lo àwọn ọ̀rọ̀ rere nígbàtí a bá nbá àwọn ẹlòmíràn sọ̀rọ̀.
Ó wí bákannáà pé a níláti ní ìgbàgbọ́ nínú Jésù Krístì.
Ó kọ́ni pé a níláti ṣe àwọn àṣàyàn rere, bíi ríran àwọn ẹlòmíràn lọ́wọ́.
Kíkùn Ojú-ewé
Mo Lè Tẹ̀lé Jésù
Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott
Mo lè tẹ̀lé Jésù Krístì nípa fífetísílẹ̀ sí wòlíì.
© 2023 nípasẹ̀ Intellectual Reserve, Inc. Gbogbo ẹ̀tọ́ ní a pamọ́. A tẹ̀ẹ́ ní USA. Àṣẹ Èdè Gẹẹsì: 6/19. Àṣẹ Ìyírọ̀padà: 6/19. Ìyírọ̀padà ti Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì, Oṣù Kẹwa 2023. Language. 19048 779