Kíni Àdúrà jẹ́? Fríẹ́ndì, Oṣù Kẹ́rin, 2024, 46–47.
Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Frẹ́ndì , Oṣù Kẹ́rin, 2024
Kíni Àdúrà jẹ́?
Àdúrà ni bí a ṣe nsọ̀rọ̀ pẹ̀lú Baba Ọ̀run.
A lè gbàdúrà nígbàkugbà, níbikíbi. Baba Ọ̀run yíò gbọ́ wa nígbàgbogbo.
À nlo àwọn ọ̀rọ̀ tí ó fi ìfẹ́ àti ọ̀wọ̀ hàn nígbàtí a bá ngbàdúrà.
A dúpẹ́ Baba Ọ̀run fún àwọn ìbùkún wa. A sì lè bèèrè lọ́wọ́ Rẹ̀ fún ìrànlọ́wọ́.
Mo lè ní ìmọ̀lára ifẹ́ ti Baba Ọ̀run ní ẹ̀ẹ̀kọ̀ọ̀kan tí mo bá gbàdúrà!
© 2024 nípasẹ̀ Intellectual Reserve, Inc. Gbogbo ẹ̀tọ́ ní a pamọ́. A tẹ̀ẹ́ ní USA. Àṣẹ Èdè Gẹẹsì: 6/19. Àṣẹ Ìyírọ̀padà-èdè: 6/19. Ìyírọ̀padà-èdè ti Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì, Oṣù Kẹ́rin 2024. Language. 19288 779