2021
Ó Wá
Oṣù Kejìlá 2021


“Ó Wá,” Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́, Oṣù Kejìlá 2021.

Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fún Okun àwọn Ọ̀dọ́, Oṣù Kejìlá 2021.

Ó

Ẹkọ́ àti Àwọn Májẹ̀mú jẹri pé Jésù Krístì wá sí ayé Ó sì kọwa ní ẹnití Òun í ṣe àti ohun tí Ó mú wá fún gbogbo ènìyàn.

A Bí I Ní Ilẹ̀-ayé.

Àwòrán
ìyá àti ọmọ

Gbígbé kalẹ̀, láti ọwọ́ Jenedy Paige

Ó Wá láti Ṣe Ìfẹ́ ti Baba

Àwòrán
Jésù Krístì nkọ́ni

Ní Ilẹ̀-ayé bí Ó Ti Wà ní Ọrun, láti ọwọ́ Justin Kunz

Ó Kọ́ ẹ̀kọ́ Ó sì Dàgbà

Àwòrán
Jésù ọmọ pẹ̀lú Jósẹ́fù nṣe iṣẹ́ kápẹ́ntà

Ọmọ náà sì Dàgbà Ó sì Di Alágbára nínú Ẹ̀mí, láti ọwọ́ Walter Rane

Ó Wá láti Ra Gbogbo Ènìyàn Padà

Àwòrán
Krísti ní Gẹ́tsémánì

Krísti ní Gẹ́tsémánì, láti ọwọ́ Michael Malm

Ó Rán Àwọn Míràn Láti Jẹri nípa Rẹ̀

Àwòrán
Àwọn ángẹ́lì nkéde ìbí Krístì sí àwọn olùṣọ́ ẹran

Àpèjúwe láti ọwọ́ Justin Kunz

Òun ni Ìmọ́lẹ̀.

Àwòrán
Ọmọ ọwọ́

Ọ̀dọ́ Àgùtàn Kékeré, lati ọwọ́ Jenedy Paige

Tẹ̀