Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́
Ìbùkún Babanlá Yín
Oṣù Keje 2024


“Àwọn Ọ̀rọ̀ láti Gbé Nípasẹ̀,” Fún okun Àwọn Ọ̀dọ́, Oṣù Kéje 2024.

Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fún Okun àwọn Ọ̀dọ́ , Oṣù Kéje 2024.

Ìbùkún Babanlá Yín

Tí a yọ látinú àwọn ọ̀rọ̀ ìpàdé àpapọ̀ Oṣù Kẹ́rin 2023 nípasẹ̀ Alàgbà Kazuhiko Yamashita àti Alàgbà Randall K. Bennett ti Àádọ́rin.

ọ̀dọ́mọkùnrin

Àwọn ìjúwe láti ọwọ́ Guev

  • Ní ìmọ̀ràn ti araẹni láti ọ̀dọ̀ Olúwa sí yín nínú.

  • Igi ẹbí

    Kéde ìran yín nínú ilé Ísráẹ́lì.

  • àwọn ìwé mímọ

    Jẹ́ iwé mímọ́ araẹni.

  • Tì

    Jẹ́ mímọ́ àti ìkọ̀kọ̀.

  • yíyàwòrán

    Kò ya àwòrán ìgbé ayé yín.

  • kọ́kọ́rọ́ ìdáhùn

    Ko dáhùn gbogbo àwọn ìbèèrè yín.

Bí kò bá mẹnuba ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì kan ní ìgbé ayé, ẹ máṣe rí èyí láti túmọ̀ sí pé ẹ kò ní ní ànfààní náà. Ìbùkún babanlá jẹ́ ti ayérayé, àti pé bí ẹ bá gbé ní yíyẹ, àwọn ìlérí ti kò bá wá sí ìmúṣẹ nínú ayé yí yío jẹ́ fífúnni ní èyi tí nbọ̀.

àwọn obìnrin

Báwoni Ó Níláti Dàgbà Tó?

  • Ó níláti dàgbà tó látí ní ìmọ̀ pàtàkì àti ìwà mímọ́ ti ìbùkún náà àti láti ní ìmọ̀ kókó ẹ̀kọ́ ìhìnrere.

  • Lódodo ó níláti jẹ́ ọ̀dọ́ tó tí wọ́n mọ̀ pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìpinnu ní ayé ṣì wà níwájú.

Àwọn ìbùkún látinú Ìbùkún Yín