Oṣù Kárún 2021 Ààrẹ Russell M. NelsonKrístì Ti Jínde; Ìgbàgbọ́ nínú Rẹ̀ Yíò Ṣí àwọn Òkè NláÀàrẹ Nelson jẹri nípa agbára ìgbàgbọ́ nínú Jésù Krístì láti ràn wá lọ́wọ́ láti borí àwọn ìpènijà ayé. Ó daba àwọn ọ̀nà marun láti gbèrú sínú ìgbàgbọ́ alágbára jùlọ. Ààrẹ Dallin H. OaksKínni Olùgbàlà Wa Ti Ṣe fún Wa?Àwọn àyọsọ látinú ọ̀rọ̀ kan láti ọwọ́ Ààrẹ Dallin H. Oaks ní ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Oṣù Kẹ́rin 2021. Ààrẹ Henry B. EyringMo Fẹ́ láti Rí Tẹ́mpìlìÀwọn àyọsọ látinú ọ̀rọ̀ kan láti ọwọ́ Ààrẹ Henry B. Eyring ní ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Oṣù Kẹ́rin 2021.