Jésù Krístì
Ìbùkún Lóri Omi


Ìbùkún Lóri Omi

A! Ọlọ́run, Bàbá Ayérayé,
àwá bèrè lọ́wọ́ yin, ní orúkọ Ọmọ yín, Jésù Krístì,
pé kí ẹ bùkún kí ẹ sì yà omi
yĩ sí mímọ́ fún ọkàn gbogbo àwọn tí ó mu nínú rè,
láti lè ṣe é ní ìrántí ẹ̀jẹ̀ Ọmọ yín,
èyítí a ta sílẹ̀ fún wọn; láti lè jẹ̃rí sí yín,
A! Ọlọ́run, Bàbá Ayérayé,
pé wọ́n ńṣe ìrántí rẹ̀ nígbàgbogbo,
kí wọ́n ó lè ní Ẹ̀mí rẹ̀ pẹ̀lú wọn.
Àmín.

Tẹ̀