2014
Wá Àwọn Ọ̀nà Láti Sìn
Oṣù Kẹ́ta Ọdún 2014


Àwọn Ọmọdé

Wá Àwọn Ọ̀nà Láti Sìn

O lè yàn láti tẹ̀lé Jésù Krístì àti láti sin àwọn ẹlòmíràn. Ya àwọrán kan tí ara rẹ tí ó ńsin ọmọ ẹbí kan, kí o sì gbé àwòrán rẹ síbi tí ó ti lè rán ọ létí láti jẹ́ onínú rere lójojúmọ́.

Tẹ̀