Àwọn Ọmọdé
Ìpèníjà Inúrere Náà
Nígbàtí Jésù bẹ àwọn ènìyàn ti Amẹríkà wò, Ó kọ́ wọn láti fẹ́ràn ara wọn àti láti ní inúrere. Kíni ẹ lè ṣe láti tẹ̀lé Jésù kí ẹ sì fẹ́ràn àwọn ẹlòmíràn? Ìwọ̀nyí ni àwọn èrò díẹ̀. Ẹ Fi àmì sí ìpèníjà kọ̀ọ̀kan bí ẹ ṣe nlọ.
-
□ Mo lè dì mọ́ ẹnìkan tí ó banújẹ́.
-
□ Mo lè ṣiṣẹ́ sin ẹnìkan ní ìkọ̀kọ̀.
-
□ Mo lè kà tàbí wo ọ̀rọ̀ ìpàdé kan nípa níní inúrere.
-
□ Mo lè kọ orin Alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ kan fún ẹbí mi.
-
□ Mo lè rẹ́rín sí ẹnìkan tí ó dàbíi àdánìkanwà.
-
□ Mo le ṣeé __________________________________________.
-
□ Mo le ṣeé __________________________________________.