2016
ìpèníjà- inúrere-náà
OṢù ṢẸ́rẹ́ 2016


Àwọn Ọmọdé

Ìpèníjà Inúrere Náà

Nígbàtí Jésù bẹ àwọn ènìyàn ti Amẹríkà wò, Ó kọ́ wọn láti fẹ́ràn ara wọn àti láti ní inúrere. Kíni ẹ lè ṣe láti tẹ̀lé Jésù kí ẹ sì fẹ́ràn àwọn ẹlòmíràn? Ìwọ̀nyí ni àwọn èrò díẹ̀. Ẹ Fi àmì sí ìpèníjà kọ̀ọ̀kan bí ẹ ṣe nlọ.

  • □ Mo lè dì mọ́ ẹnìkan tí ó banújẹ́.

  • □ Mo lè ṣiṣẹ́ sin ẹnìkan ní ìkọ̀kọ̀.

  • □ Mo lè kà tàbí wo ọ̀rọ̀ ìpàdé kan nípa níní inúrere.

  • □ Mo lè kọ orin Alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ kan fún ẹbí mi.

  • □ Mo lè rẹ́rín sí ẹnìkan tí ó dàbíi àdánìkanwà.

  • □ Mo le ṣeé __________________________________________.

  • □ Mo le ṣeé __________________________________________.

Tẹ̀