Àwọn Ọmọdé
Ìrànlọ́wọ́ ti Bàbá Ọ̀run
Ìtànlọ́wọ́ ti Bàbá Ọ̀run Nítorí Bàbá Ọ̀run nífẹ́ wa, Ó ti fún wa ní ọ̀pọ̀lọlọ àwọn ohun èlò, tàbí ẹ̀bùn, láti ràn wá lọ́wọ́. Nísàlẹ̀ ni díẹ̀ lára àwọn ẹ̀bùn tí Ó ti fún wa.
-
Báwo ni ẹ́ ṣe lè lo àwọn ẹ̀bùn wọ̀nyí láti bùkún ìgbé ayé yín àti láti bùkún àwọn ẹlòmíràn?
-
àdúrà
-
Ìfẹ́ fún àwọn ẹlòmíràn
-
Àwọn àpọ́stélì àti wòlíì
-
àwọn ìwé mímọ