2016
Fífi Ìfẹ́ hàn
OṢù Owewe 2016


Àwọn Ọmọ

Fífi Ìfẹ́ hàn

Jésù ṣe àbápín ìtàn kan nípa bàbá kan àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ méjì Bàbá náà nṣiṣẹ́ nínú ọgbà ajarà kan ó sì ní kí àwọn ọmọkùnrin méjèèjì ran òun lọ́wọ́. Ọmọkùnrin àkọ́kọ́ sọ pé rárá lákọ́kọ́ ṣùgbọ́n nígbẹ̀hìn ó padà wá láti ràn àn lọ́wọ́ nínú ọgbà ajarà. Ọmọkùnrin èkeji sọ pé òun ó ṣèrànwọ́, ṣùgbọ́n kò ṣeé rárá. Jésù kọ́ni pé ọmọkùnrin àkọ́kọ́ ni ó fi ìfẹ́ hàn jù fún Bàbá rẹ̀ nípa gbígbọ́ran.

Ẹ ṣe ìṣe ìtàn yí ! Nígbànáà kọ tàbí ya àwòrán ohun mẹ́ta tí ẹ lè ṣe láti fi ìfẹ́ yín hàn fún Bàbá Ọ̀run.

Tẹ̀