Àwọn Ọmọdé
Yan Òtítọ́ náà
Yíyan òtítọ́ náà nmú wa súnmọ́ Bàbá Ọ̀run àti Jésù Krístì síi Bákannáà ó nrànwá lọ́wọ́ láti ní ìdùnnú àti ààbò. Ẹ yí àkámọ́ sí àwọn ọ̀nà tí ẹ fi lè yan òtítọ́.
Ṣe ìrẹ́jẹ ní ilé ìwé
Ka àwọn ìwé mímọ
Lọ sí ilé ìjọsìn
Ta ayò rere
Jà pẹ̀lú àwọn arákùnrin àti arábínrin rẹ
Sin àwọn ẹlòmíràn