2016
Wá sí ọ̀dọ̀ Krístì
OṢù Ọ̀pẹ̀ 2016


Àwọn Ọmọdé

Wá sí ọ̀dọ̀ Krístì

Olùgbàlà ti ṣe ìlérí àláfíà fún wa nígbàtí a ba wá sí ọ̀dọ̀ [Rẹ̀]” (Matthew 11:28) Èyí túmọ̀ sí títẹ̀lé àpẹrẹ Rẹ̀ àti títiraka láti dúró nítòsí Rẹ̀.

  • Ní ìbọ̀wọ̀ fún ní àsìkò oúnjẹ Olúwa.

  • Ẹ yàn láti jẹ́ onínú rere kí ẹ má sì ṣe dá àwọn ẹlòmíràn lẹ́jọ́.

  • Kà nípa Olùgbàlà nínú àwọn ìwé mímọ́

Àpèjúwe láti ọwọ́ Casey Nlson

Tẹ̀