2017
Àwọn Ìkọ́ni fún Ìgbà Tiwa
May 2017


Àwọn Ìkọ́ni fún Ìgbà Tiwa

Láti Osù Kárún Ọdún2016 sí Osù Kẹwá Ọdún 2016 Àwọn Ẹkọ Oyè Àlùfáà Mẹlkìsédékì àti Ẹgbẹ Ìrànlọwọ ní Ọjọọjọ Ìsinmi Kẹrín ni a pèsè láti inú àwọn ìsọrọ kan tàbí jù bẹẹ lọ tí a fifúnni nínú ìpàdé àpapọ̀ gbogboògbò Osù Kẹrin Ọdún 2016 Ní oṣù kẹwá ọdún 2016 a lè yan àwọn ọrọ bóyá láti inú ìpàdé àpapọ̀ gbogbogbò oṣù kẹrin tàbí oṣù kẹwá ọdún 2016 Àwọn Ààrẹ Eèkàn àti Ẹkùn yío yan àwọn ọ̀rọ̀ èyí tí wọn yíò lò ní agbègbè wọn, tàbí wọn lè gbé ojúṣe yí lé àwọn Bíṣọọpù àti àwọn ààrẹ ẹka lọwọ.

Àwọn ọrọ náà wà ní onírũrú èdè ní conference.lds.org.

Tẹ̀