2017
Àwọn Ìsopọ̀ ti Ìfẹ́
October 2017


Àwọn Ọmọ

Àwọn Ìsopọ̀ ti Ìfẹ́

Nígbàtí a bá ka àwọn ìwé mímọ́ tàbí gbàdúrà, a le ní ìmọ̀lára bí Bàbá Ọ̀run àti Jésù ṣe fẹ́ràn wa tó. Ya àwọn ọkàn kéékèèké sínú ọkàn nlá kan. Kun inú ọkàn kan ní gbogbo ìgbá tí ó bá gbàdúrà tàbí ka àwọn ìwé mímọ́ rẹ̀. Kíni o tún lè ṣe laáti ní imọ̀lára sísúnmọ́ Bàbá Ọ̀run àti Jésù?

Tẹ̀