2017
Ṣíṣọ́nà Fún Jésù
December 2017


Àwọn Ọmọdé

Ṣíṣọ́nà Fún Jésù

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ṣọ́nà wọ́n sì dúró fún ìbí Jésù. Bayii à nṣọ́nà a sì ndúró fun Un láti wá lẹ́ẹ̀kan si! A lè ṣetán nípa kíkọ́ nípa Jésù àti títẹ̀lé E. Báwo ni ẹ ṣe ntẹ̀lé Jésù? Ya ìràwọ̀ kan kí o sì kọ àwọn èrò rẹ sínú rẹ̀

Tẹ̀