Oṣù Kejì (Erele) 2022 Àwọn Májẹ̀mú Sowápọ̀ pẹ̀lú Ọlọ́runKíni àwọn májẹ̀mú? Ìgbà wo ni kí a dá àwọn májẹ̀mú? Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ Fún Ọ̀dọ́: Àwọn Bàbánlá náà: Ẹni Tí Wọ́n Jẹ́ àti Ìdí Tí Ó Fi Ṣe KókóGba àlàyé ní ṣókí nípa ẹni ti Ábráhámù, Ísákì àti Jákọ́bù jẹ́ àti ìdí tí wọ́n fi ṣe pàtàkì sí wa lóni. Fríẹ́ndì Fún Ọmọdé: Ábráhámù àti Sáràh