“Àwọn Ìlérí Ezekiel Wá Sí Ìmúṣẹ,” Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì, Oṣù Kẹwa 2022
“Àwọn Ìlérí Ezekiel Wá Sí Ìmúṣẹ”
Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì, Oṣù Kẹwa 2022
Àwọn Ìlérí Ezekiel Wá Sí Ìmúṣẹ
Ezekiel jẹ́ wòlíì kan. Ọlọ́run fi àwọn ohun pùpọ̀ ọjọ́ ọ̀la hàn án tí kò tíì ṣẹlẹ̀ síbẹ̀síbẹ̀. Ezekiel kọ wọ́n sílẹ̀.
Ezekiel kọ̀wé nípa àwọn ìwé méjì tí á ó tẹ̀jáde nì ọjọ́-kan. Ìwé kan ni Bíbélì. Ìwé míràn ni Ìwé ti Mọ́mọ́nì.
Ní ọ̀pọ̀ ọdún lẹ́hìnnáà, Bíbélì di títẹ̀ jáde.
Lẹ́hìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún si, Joseph Smith ṣe ìyírọ̀padà Ìwé ti Mọ́mọ́nì. Ìran Ezekiel Wá Sí Ìmúṣẹ!
Ní òní a lè ka Bíbélì àti Ìwé ti Mọ́mọ́nì. Wọ́n nṣiṣẹ́ papọ̀ láti kọ́ni nípa Jésù Krístì.
Nígbàtí mo bá ka àwọn ìwé mímọ́, èmi nkọ́ nípa Jésù Krístì.
© 2022 láti ọwọ́ Intellectual Reserve, Inc. Gbogbo àwọn ẹ̀tọ́ ni a fipamọ́. A tẹ̀ẹ́ ní USA. Àṣẹ Èdè Gẹẹsì: 6/19. Àṣẹ Ìyírọ̀padà: 6/19. Ìyírọ̀padà ti Ọ̀rọ̀ Fríẹ̀ndì Oṣooṣù, Oṣù Kẹ́wàá 2022. Yoruba 18317 779