Oṣù Kẹ́wàá (Ọ̀wàwà) 2022 Ààrẹ Russell M. NelsonMájẹ̀mú àìlópinÀàrẹ Nelson kọ́ni pé àwọn wọnnì tí wọ́n ti dá májẹ̀mú pẹ̀lú Ọlọ́run ní ààyè sí irú ìfẹ́ àti áánú pàtàkì kan àti pé a tì pè wá ní àkokò yí nínú àkọọ́lẹ̀-ìtan láti kọ́ aráyé nípa ẹwà àti agbára ti májẹ̀mú titun ati àìlópin náà. Fún Okun àwọn Ọ̀dọ́ Fún àwọn Ọ̀dọ́: Ẹ Kọ́ Nípa Jésù Krístì kí ẹ sì Ní Ààyè sí Agbára Rẹ̀Iwé ìkéde onímísí kan nípa bí agbára Krístì ṣe nmú àláfíà wá. Fríẹ́ndì Fún Àwọn Ọmọdé: Àwọn Ìlérí Ezekiel Wá sí ÌmúṣẹẸ kọ́ nípa wòlíì Ezekiel látinú Májẹ̀mú Láéláé.