2023
Iṣẹ́-ìyanu Tabitha
Oṣù Kẹsan 2023


“Iṣẹ́-ìyanu Tabitha,” Fríẹ́ndì, Oṣù Kẹsan 2023, 46–47.

Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ̀ndì, Oṣù Kẹsan 2023

Iṣẹ́-ìyanu Tabitha

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Àwọn ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Tàbíthà jẹ́ àtẹ̀lé Jésù Krístì Ó rán àwọn aṣọ àti kóòtù ó sì ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ohun rere fún àwọn ẹlòmíràn.

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Ṣùgbọ́n nígbànáà Tàbíthà ṣe àárẹ̀ ó sì kú. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn banújẹ́.

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Wòlíì, Pétérù, lọ sọ́dọ̀ Tàbíthà. Ó jí i dìde kúrò nínú òkú pẹ̀lú agbára tí Jésù Krístì fún un.

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà

Tàbíthà wà láàyè lẹ́ẹ̀kansi! Òun lè ránṣọ́ ó sì lè sìn bákannáà lẹ́ẹ̀kansì. Ó jẹ́ iṣẹ́-ìyanu kan.

Kíkùn Ojú-ewé

Mo Lè Sìn Àwọn Ẹlòmíràn

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà níhin

Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Mo lè fẹ́ràn bí ti Jésù Krístì nípa sísin àwọn ẹlòmíràn.

Tẹ̀