2013
Yàn láti Dúró Jẹ́
March 2013


Àwọn Ọmọdé

Yàn láti Dúró Jẹ́

Ààrẹ Monson wípé nígbà tí a bá dúró jẹ́ tí a sì ní ìdájẹ́kẹ́ tọlọ́wọ̀, a lè ní ìmọ̀-inú àláfíà sì jèrè ẹ̀rí tí ó lágbára síi nípa Bàbá Ọ̀run wa. Àti pé Ẹ̀mí Mímọ́ lè tún bọ̀ tọ́ wa nípa àwọn ọ̀nà tí a lè ran àwọn ẹlòmíràn lọ́wọ́.

Kọ sílẹ̀ tàbí jíròrò pẹ̀lú àwọn òbí rẹ ọ̀nà kan tí o lè dúró jẹ́. Lẹ́hìn náà lo àsìkò ní ọ̀sẹ̀ yí láti dán wò. Lẹ́hìn tí o bá ṣe é, o lè kọ sílẹ̀ nínú ìwé àkọsílẹ̀ rẹ nípa àwọn ìmọ̀-inú àti àwọn ìtọ́sí tí o ní.

Tẹ̀