Àwọn Ọmọdé
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ọ̀nà láti Sọ O Sé
“Káà kiri àgbáyé ní ìparí òòjọ́,
Àwọn ọmọ Bàbá Ọ̀run kúnlẹ̀ láti gbàdúrà,
Olúkúlùkù ń sọ pé o ṣé ní ọ̀nà àkànṣẹ rẹ̀
“Children All Over the World,” Children’s Songbook, 16.
Lo àwòràn ayé láti ṣe ìdámọ̀ àwọn oríṣiríṣi orílẹ̀ èdè níbi ti a tí ń sọ àwọn èdè wọ̀nyí. À á ń sọ lára àwọn èdè wọ̀nyí ní ju orílẹ̀ èdè kan lọ!
-
gracias (Spanish)
-
malo (Tongan)
-
thank you (English)
-
shukriyaa (Hindi)
-
spaseba (Russian)
-
arigatō (Japanese)
-
obrigado (Portuguese)
-
asante (Swahili)
-
merci (French)