2013
Àwọn ọ̀nà láti gbànisílẹ̀
October 2013


Àwọn Ọmọdé

Àwọn ọ̀nà láti Gbanisílẹ̀

Ààrẹ Thomas S. Monson ti kọ́ pé a gbúdọ̀ nawọ́ jáde sí àwọn ẹlòmíràn, pẹ̀lú àgbàlagbà, opó, aláìsàn, ẹni tó láápọn kéréjù, àti àwọn tí ó nílò àfikún ìrànlọ́wọ́. Ronú nípa àwọn ènìyàn tí o mọ̀ tí ó lè lo àwọn sísìn.

Kọọ́ sílẹ̀ tàbí kí o ya àwọn àwòrán ti àwọn iyè inú fún àwọn ọ̀nà tí o lè fi ran díẹ̀ lọ́wọ́ lára àwọn ènìyàn yí. O lè bèèrè lọ́wọ́ àwọn òbí rẹ láti ràn ọ́ lọ́wọ́ ronú ti àwọn iyè inú àti pé nígbà náà kí o yan ìkan láti gbà níyànjú ní ọ̀sẹ̀ yí.

Tẹ̀