2014
Àwọn Ìkọni fún Ìgbà Tiwa
May 2014


Àwọn Ìkọni fún Ìgbà Tiwa

Láti oṣù kárun ọdún 2014 sí oṣù kẹ́wá ọdún 2014, àwọn ẹ̀kọ́ ọjọ ìsinmi kẹ́rin lóṣù ti Oyè àlùfáà Mẹlkisédékì àti Ẹgbẹ́ Aranilọ́wọ́ ni a gbọ́dọ̀ pèsè láti inú ìkan tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ lára àwọn ọ̀rọ̀ Ọlọrun tí a fifúnni ní ìpàdé gbogbogbò oṣù kẹ́rin ọdún 2014. Ní oṣù kẹ́wá ọdún 2014, a lè yan àwọn ọ̀rọ̀ bóyá láti inú ìpàdé gbogbogbò oṣù kẹ́rin ọdún 2014 tàbí oṣù kẹ́wá ọdún 2014. Àwọn Alákóso Eèkàn àti Ẹ̀kùn gbọ́dọ̀ yan àwọn ọ̀rọ̀ èyí tí wọn yíò lò ní agbègbè wọn, tàbí wọ́n lè gbé ojúṣe yí lé àwọn Bíṣọ́ọ̀bù àti àwọn Alákóso ẹ̀ka lọ́wọ́ gẹ́gẹ́bí aṣojú.

Àwọn ọ̀rọ̀ náà wà ní oniruru èdè ní conference.lds.org.

Tẹ̀