Àwọn Ọmọ Kíkọ́ nípa Jésù Ẹ̀mí Mímọ́ nfún wa ní àwọn ìmọ̀lára tí ó ní àláfíà láti rànwá lọ́wọ́ láti mọ̀ pé Jésù jẹ́ òtítọ́ àti pé ó nífẹ́ wa. Kọ sílẹ̀ tàbí ya àwòrán ohun kan tí ẹ̀yin yíò níláti kọ́ nípa Jésù.