2017
Àwọn Wòlíì Ntọ́ Wa Sí Ọ̀dọ̀ Krístì
September 2017


Àwọn Ọmọdé

Àwọn Wòlíì Ntọ́ Wa Sí Ọ̀dọ̀ Krístì

Olùgbàlà fún wa ní àwọn wòlíì nítorí Ó ní ìfẹ́ wa. Títẹ̀lé àwọn wòlíì nràn wá lọ́wọ́ láti yan èyí tí ó tọ́. Kíni áwọn ohun méjì tí ẹ lè ṣe láti tẹ̀lé wòlíì?

Tẹ̀