2017
Àwọn Ìkọ́ni fún Ìgbà Tiwa
November 2017


Àwọn Ìkọ́ni fún Ìgbà Tiwa

Láti oṣù kọkànlá ọdún 2017 sí oṣù kẹrin ọdún 2018 àwọn ẹkọ ti Oyè àlùfáà Mẹlkisédékì àti Ẹgbẹ Ìrànlọwọ ní ọjọ ìsinmi kẹrin nmúrasílẹ láti inú ọ̀kan tàbí jùbẹẹ lọ lára àwọn ọ̀rọ̀ tí a fi fúnni ní ìpàdé àpapọ̀ gbogbogbòò ti oṣù kẹwàá ọdún 2017. Ní oṣù kẹrin ọdún 2018 a lè yan àwọn ọrọ bóyá láti inú ìpàdé àpapọ̀ gbogbogbò oṣù kẹrin tàbí oṣù kẹwá. Àwọn Ààrẹ Eèkàn àti Ẹkùn gbọ́dọ̀ yan àwọn ọ̀rọ̀ èyítí wọn yíò lò ní agbègbè wọn, tàbí wọn lè gbé ojúṣe yí lé àwọn Bíṣọọpù àti àwọn Ààrẹ ẹ̀ka lọwọ.

Àwọn ọrọ náà wà ní onírũrú èdè ní conference.lds.org.

Tẹ̀