Àwọn Ọmọdé
Ẹ Múrasílẹ̀ fún Ìpàdé Àpapọ̀!
Kọ àwọn ìṣílétí wọ̀nyí sí orí ẹ̀là ìwé kan. Tọ́jú ìwé náà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ìpàdé àpapọ̀ kí o lè kọ àwọn ohun tí o kọ́ sílẹ̀.
-
Kọ àwọn ìbèèrè rẹ̀ sílẹ̀. Mo nronú nípa …
-
Gbàdúrà sí Bàbá Ọ̀run. Èmi yíò fẹ́ràn ìrànwọ́ láti kọ́ nípa …
-
Fi etí sílẹ̀ sí ìpàdé àpapọ̀ gbogbogbò. Mo kọ́ ẹ̀kọ́ …