2018
Ẹ Múrasílẹ̀ fún Ìpàdé Àpapọ̀!
March 2018


Àwọn Ọmọdé

Ẹ Múrasílẹ̀ fún Ìpàdé Àpapọ̀!

Kọ àwọn ìṣílétí wọ̀nyí sí orí ẹ̀là ìwé kan. Tọ́jú ìwé náà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ìpàdé àpapọ̀ kí o lè kọ àwọn ohun tí o kọ́ sílẹ̀.

  • Kọ àwọn ìbèèrè rẹ̀ sílẹ̀. Mo nronú nípa …

  • Gbàdúrà sí Bàbá Ọ̀run. Èmi yíò fẹ́ràn ìrànwọ́ láti kọ́ nípa …

  • Fi etí sílẹ̀ sí ìpàdé àpapọ̀ gbogbogbò. Mo kọ́ ẹ̀kọ́ …

Tẹ̀