2021
Jésù Sọ láti Pín Ìhìnrere náà
Oṣù Kẹ́jọ 2021


Jésù Sọ láti Pín Ìhìnrere náà,” Fríẹ́ndì, Oṣù kẹ́jọ 2021

Jésù Sọ láti Pín Ìhìnrere náà”

Àwọn Ìtàn Májẹ̀mú Titun fún àwọn Ọ̀dọ́ Olùkàwé

Jésù Sọ láti Pín Ìhìnrere náà

Máttéù 28 àti Ìṣe Àwọn Àpóstélì 1

Àwòrán
Jésù tó jínde nbá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀

Lẹ́hìn ti Jésù kú tí ó sì jìnde, Ó bẹ àwọn tí wọ́n ntẹ̀le E wò. Ó wí fún àwọn Àpóstélì Rẹ láti kọ́ gbogbo ènìyàn láti pa àwọn òfin mọ́ kí wọn ó sì jẹ́ rírìbọmi.

Àwòrán
Jésù tó jínde nbá Pétérù sọ̀rọ̀

Pétérù ni wòlíì nísisìyí tí yio darí Ìjọ náà ní ilẹ̀ ayé. Jésù ṣèlérí pé Ẹ̀mí Mímọ́ yio wà pẹ̀lú wọn.

Àwòrán
Jésù npadà sí ọ̀run

Lẹ́hìn kíkọ́ àwọn tí wọ́n ntẹ̀le E, Jésù padà sí ọ̀run

Àwòrán
àwọn àpóstélì arìnrìnàjo

Àwọn Àpóstélì bẹ̀rẹ̀ rírin ìrìnàjò àti kíkọ́ àwọn ènìyàn ní oríṣiríṣi àwọn ilẹ̀.

Àwòrán
àwọn ọmọde ní ìpàgọ́

Èmi náà lè ṣè ìranlọ́wọ́ láti pín ìhìnrere bákanáà. Èmi lè jẹ́ ọ̀rẹ́ rere kan kí nsì dúró fún ohun tí ó tọ́.

Kíkùn Ojú-ewé

Jésù Fẹ́ Kí Èmi Pín Ìhìnrere náà

Àwòrán
Ọmọ kan npín ẹ̀dà Fríẹ́ndì pẹ̀lú ẹlòmíràn

Tẹ̀ àwòrán náà láti ṣe ìgbàsílẹ̀.

Àwọn Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Tẹ̀