“Àwọn Lẹ́tà Páùlù” Àwọn Ìtàn Májẹ̀mú Titun fún àwọn Ọ̀dọ́ Olùkàwé, 2019
“Àwọn Lẹ́tà Páùlù”
Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Frẹ́ndì, , Oṣù Kẹ́san 2021
Àwọn Lẹ́tà Páùlù
Àpọ́stélí Páùlù ṣé ìrànlọ́wọ́ láti darí Ìjọ lẹ́hìn tí Jésù padà lọ sí ọrun. Nígbànáà sẹ́hìn, kò sí tẹlifóònì tàbí íntánẹ́ẹ̀tì. Nítorínáà Páùlù kọ lẹ́tà sí àwọn ọmọ Ìjọ.
Páùlù kọ̀wé sí àwọn ènìyàn tí ó wà ní ìlú Kọ́ríntì. Ó wí fún wọn kí wọ́n dáríji àwọn ẹlómíràn. Ó wí fún wọn kí wọ́n ní sùúrù. Ó kọ̀wé nípa Jésù.
Páùlù kọ̀wé sí àwọn ènìyàn tí ó wà ní ìlú Galátíà. Ó wí fún wọn kí wọ́n fẹ́ràn ọmọnìkejì wọn. Ó sọ fún wọn bí Ẹ̀mí ṣe rí lára.
Àwọn lẹ́tà Páùlù ṣe pàtàkì tí ó fi jẹ́pé wọ́n di ará Bíbélì. O lè kà wọ́n nínú Májẹ̀mú Titun.
Mo lè kẹkọ láti inú àwọn ìkọ́ni Páùlù. Èmi yío fetísílẹ̀ sí ohun tí wòlí àti àwọn àpọ́stélì nkọ́ni lónìí!
© 2021 nípasẹ̀ Intellectual Reserve, Inc. Gbogbo ètọ́ ni a fi pamọ́. A tẹ̀ẹ́ ní USA. Àṣẹ Èdè Gẹẹsì: 6/19. Àṣẹ Ìyírọ̀padà-èdè: 6/19. Ìyírọ̀padà-èdè ti Ọ̀rọ̀ Fríẹ́ndì, Oṣù Kẹ́san 2021. Yoruba 17471 000