2022
Elíjà àti Ohùn Jẹ́jẹ́, Kékeré náà
Oṣù Kẹfà 2022


“Elíjà àti Ohùn Jẹ́jẹ́, Kékeré náà” Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì , Oṣù Keje 2022

“Elíjà àti Ohùn Jẹ́jẹ́, Kékeré náà”

Àwọn Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì, Oṣù Kéje 2022

Elíjà àti Ohùn Jẹ́jẹ́, Kékeré náà

Àwòrán
Elíjà ní ẹ̀gbẹ́ òkè kan

Àwọn Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Ábráhámù jẹ́ wòlíì nlá kan. Ó fẹ́ gbọ́ ohun Ọlọ́run. Ó lọ sí orí òkè kan láti gbọ́ ohùn Ọlọ́run dáradára.

Àwòrán
Elíjàn nrí ìjì líle kan

Ìjì líle kan wà. Ó le tó bẹ́ẹ̀ tí ó fọ́ àwọn àpáta. Ìjì náà jẹ́ aláriwo. Ṣùgbọ́n kìí ṣe ohùn Ọlọ́run.

Àwòrán
Elíjà nrí ilẹ̀ ríri àti iná.

Ní títẹ̀lé ilẹ̀ ríri kan wà. Ilẹ̀ ayé mì tìtì. Iná kan wà níbẹ̀ pẹ̀lú. O ní àwọn iná nlá. Ṣùgbọ́n ilẹ̀ ríri àti iná náà kìí ṣe ohùn Ọlọ́run.

Àwòrán
Elíjà ngbọ́ ohùn jẹ́jẹ́, kékeré náà

Nígbànáà ìdákẹ́rọ́rọ́ wà Elíjà gbọ́ ohùn Ọlọ́run Ó jẹ́ jẹ́jẹ́ àti kékeré Ṣùgbọ́n ó ṣe kedere.

Àwòrán
àwọn ènìyàn ni ilé ìjọsìn

Mo le gbọ́ ohùn Ọlọ́run nípa fífi etí sílẹ̀ sí Ẹmí Mímọ́. Ó nbá mi sọ̀rọ̀ ní àwọn ò̩nà kékeré tí ó sì rọrùn.

Kíkùn Ojú-ewé

Mo Le Ní Ìmọ̀lára Ẹmí Mímọ́

Àwòrán
Àwọn ọmọdé nkọ àwọn orin ìsìn

Tẹ̀ àwòrán náà láti ṣe ìgbàsílẹ̀.

Apejúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Kínni nràn ọ́ lọ́wọ́ láti ní ìmọ̀lára Ẹmí Mímọ́?

Tẹ̀