Oṣù Kẹfà 2024 Láti ọwọ́ Ronald A. RasbandA Pè Wá láti Ṣe RereÀ ngbé ìjọba Ọlọ̀run ga láti sin àwọn ẹlòmíràn, di ìmọ́lẹ̀ wa mú, àti dídúró fún òmìnira ẹ̀sìn. Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ Kí Ni Ohun Tí A Ṣe Ìlérí Rẹ̀ Gan Nígbàtí A Bá Ṣe Ìríbọmi?Ìdáhùn kan sí ìbèèrè náà: “Kí Ni Ohun Tí A Ṣe Ìlérí Rẹ̀ Gan Nígbàtí A Ṣe Ìríbọmi?” Fríẹ́ndì Ọlọ́run fi Òmìnira fún Álmà àti Amúlẹ́kìKa ìtàn kan nípa Álmà àti Ámúlẹ́kì àti bí Ọlọ́run ṣe ràn wọ́n lọ́wọ́ láti sá kúrò nínú túbú.