Oṣù Kẹ́jọ 2024 Dale G. RenlundỌlọ́run Yíò Tìlẹ̀hìn yíò sì Ṣaláàbò WaAlàgbà Relund kọ́ni pé àwa, bíiti Ọ̀gágun Mórónì, lè gba ìrànlọ́wọ́ tọ̀run àti agbára fún àwọn ogun tí a dojúkọ ní ayé bí a ti nbu-ọlá fún àwọn májẹ̀mú wa tí a sì npa àwọn òfin mọ́. Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ Andrea Muñoz SpannausÌbáṣepọ̀ Alàgbára KanArábìnrin Spannaus kọ́ni bí májẹ̀mú ìbáṣepọ̀ kan pẹ̀lú Baba Ọ̀run àti Jésù Krístì ti nfún wa ní ààyè si agbára Wọn. Fríẹ́ndì Àwọn Ọ̀dọ́mọkùnrin JagunjagunKa ìtàn kan nípa bí àwọn ẹgbẹ́ ọ̀dọ́ jagunjagun ti kẹkọ látọ̀dọ̀ àwọn ìyá wọn láti gbẹ́kẹ̀lé Ọlọ́run.