2016
Olùlànà ni Ìwọ Bákannáà!
OṢù Agẹmọ 2016


Àwọn Ọmọdé

Olùlànà ni Ìwọ Bákannáà!

Àwọn Olùlànà jẹ́ àwọn ènìyàn tí wọ́n ntún ọ̀nà ṣe fún àwọn ẹlòmíràn láti tẹ̀lé.

Ya àwòrán kan tàbí wá fọ́tò ọ̀kan lára àwọn bàbáńlá rẹ. Njẹ́ o lè wá ìtàn kan nípa bí wọ́n ṣe tún ọ̀nà ṣe fún ọ láti tẹ̀lé? Kọ ọ̀nà méjì tí o fi lè di olùlànà kan lóní. O lè ṣe àbápín àwọn èrò rẹ ní ìpàdé ilé ẹbí ìrọ̀lẹ́ tí ó nbọ̀!

Tẹ̀