2017
Àwọn Àkókò Inú dídùn àti Ìbànújẹ́
August 2017


Àwọn Ọmọdé

Àwọn Àkókò Inú dídùn àti Ìbànújẹ́

Àwọn ọjọ́ kan wà tí ó ní àkokò tí ó dínkù ju ìdùnún lọ. Iyẹn sì Dára Jésù lè ràn yín lọ́wọ́ láti là wọ́n kọjá.

Ẹ ya àwòrán ojú kan tí ó rún pọ̀. Báwo ni Jésù ṣe lè ràn yín lọ́wọ́ nígbà tí ẹ bá banújẹ́? Nísisìnyí ya àwòrán ojú kan pẹ̀lú ẹ̀rín. Báwo ni Jésù ṣe lè ràn yín lọ́wọ́ láti ní ìdùnnú

Tẹ̀