Oṣù Ẹ̀kẹwá 2019 Abala Òwúrọ̀ Sátidé Jeffrey R. HollandỌ̀rọ̀ náà, Ìtumọ̀ náà, àti Ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀-èrò náàAlàgbà Holland rán wa léti láti pa ìdọjúkọ wá mọ́ sórí Olùgbàlà bí gbùngbun ìgbé ayé wa nígbàgbogbo, ìgbàgbọ́, àti iṣẹ́ ìsìn wa. Terence M. VinsonÀwọn Ọmọlẹ́hìn Tòótọ́ ti OlùgbàlàAlàgbà Vinson kọ́ni nípa pàtàkì fi]farasìn láti jẹ́ ọmọlẹ́hìn Jésù Krístì kan. Stephen W. OwenẸ Jẹ́ Olóòtítọ́, Kìí ṣe Aláìgbàgbọ́Arákùnrin Owen kọ́ni bí a ṣe lè ṣìkẹ́ ẹ̀mí nípasẹ̀ gbùngbun-ilé, ikẹkọ àti ìgbé ayé ihìnrere itìlẹhìn-Ijọ. D. Todd ChristoffersonAyọ̀ àwọn Ènìyàn Mímọ́Alàgbà Christofferson kọni nípa ayọ̀ tí ó nwa látinú pípa àwọn òfin mọ́, kúrò nínú bíborí àwọn ìpenijà, àti nínú sínsìn bí Jésù ti sìn. Michelle CraigOkun ti Ẹ̀míArábìnrin Craig nkọ́ni bí a ṣe lè ṣe àlékún okun ti ẹ̀mí wa láti gba ìfihàn. Dale G. RenlundÌfarasìn Àìyẹsẹ̀ sí Jésù KrístìAlàgbà Relund kọ́ni pé Ọlọ́run pè wa láti ju ìwà atijọ nù pátápátá kúrò nínú wa kí a sì bẹ̀rẹ̀ ìgbé ayé titun nínú Krístì, ní fífi ìfarasìn wa hàn nípa dídá ati pípa awọn májẹ̀mú mọ́. Dallin H. OaksNí igbẹ́kẹ̀lé nínú Olúwa.Ààrẹ Oaks nkọ́ni pé gbígbẹ́kẹ̀lé Olúwa ni ẹ̀kọ́ ìyàn tó dárajùlọ tí a lè lò nígbàtí a bá ní àwọn ibèèrè nípa àwọn ohun tí a kò tíi fihàn síbẹ̀síbẹ̀. Abala Ọ̀sán Sátidé Henry B. EyringÌmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Aláṣẹ Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè Gbogbogbò ti ÌjọÀàrẹ Eyring gbé ìbò ìmúdúró kalẹ̀ fún àwọn olórí Ìjọ. David A. BednarṢíṣọ́ra sí Gbígba Àdúrà LéraléraLílo ológbò igbó bí àpẹrẹ àwọn apani, Alàgbà Bednar kọ́ni ní ọ̀nà mẹ́ta tí a fi lè nífura àwọn ọgbọ́n èṣù. Rubén V. AlliaudAri nípa Agbára ti Ìwé Mọ́mọ́nìAlàgbà Alliaud kọ́ni bí ìyípada ṣe lè ṣẹlẹ̀ nípa àwọn òtítọ́ alágbára nínú Ìwé ti Mọ́mọ́nì. Russell M. NelsonÀwọn Ẹlẹri, Iyejù Oyèàlùfáà Árọ́nì, àti Kíláàsì àwọn Ọ̀dọ́mọbìnrinÀàrẹ Nelson polongo àwọn àkóso iyípadà ní ìkàsí àwọn ẹ̀rí àti àtunṣe sí kíláàsì àwọn iyejú Oyèàlùfáà Áárọ́nì àti àwọn Ọ̀dọ́mọbìnrin. Quentin L. CookÀwọn Àtúnṣe láti Fún Àwọn Ọ̀dọ́ ní OkunAlàgbà Cook polongo ìyípadà àwọn ìṣètò ní ìgbìrò láti ran àwọn bìṣọ́ọ́prìkì lọ́wọ́ láti dojúkọ ojúṣe wọn láti tọ́jú àwọn ọ̀dọ́. Mark L. PaceWá, Tẹ̀lé Mi—Ètò Ìlòdì Sí Ète àti Ìronú Ṣíwájú ti OlúwaÀàrẹ Pace kọ́ni pé ṣíṣe àṣàrò Wá, Tẹ̀lé Mi ntako àwọn ìkọlù ti ọ̀tá ó sì nmú àwọn ọmọ ìjọ súnmọ́ Ọlọ́run àti àwọn ẹbí wọn. L. Todd BudgeÌgbẹ́kẹ̀lé pẹ̀lú Ìtẹramọ́ àti ÌfaradàAlàgbà Budge kọ́ni nípa gbígbẹ́kẹ̀lé Olúwa bí ó ti fiwé ìrìnàjò àwọn ara Járẹ́dì sí ìrìnàjò wa nínú ayé ikú. Jorge M. AlvaradoLẹ́yìn Ìdánwò Ìgbàgbọ́ WaAlàgbà Alvarado ṣe àbápín àpẹrẹ àwọn wọnnì tí wọ́n jẹ́ẹ̀rí àwọn iṣẹ́ ìyanu lẹ́hìn àdánwò ìgbàgbọ́ wọn. Ronald A. RasbandDídúró nípa àwọn Ilérí Wa àti àwọn Májẹ̀múAlàgbà Rasband ránwalétí bí ó ṣe pàtàkì kí a pa àwọn májẹ̀mú àti ìlérí tí a ṣe sí Olúwa àti àwọn ẹ̀lòmíràn mọ́. Ìpàdé Gbogbogbò Àwọn Obìnrin Reyna I. AburtoNínú Ìkukù àti Òòrùn, Olúwa, Bá Mi gbé!Arábìnrin Aburto jẹri pé Olùgbàlà lè ràn gbogbo àwọn ọmọ Ọlọ́run lọ́wọ́ láti farada àìlera ti-ara àti ti ọpọlọ. Lisa L. HarknessBíbu Ọlá fún Orúkọ Rẹ̀Arábìnrin Harkness kọ́ni ní ohun tó túmọ̀sí láti gbé orúkọ Jésù Krístì lé orí arawa àti láti rántí Rẹ̀ nígbàgbogbo. Bonnie H. CordonOlùfẹ́ àwọn ỌmọbìnrinArábìnrin Cordon polongo àwọn àtúnṣe sí ìṣètò àwọn Ọ̀dọ́mọbìnrin àti kíkọ́ni pé àwọn ìyípadà yíò ran àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin lọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà. Henry B. EyringÀwọn Obìnrin Májẹ̀mú nínú Iṣẹ́ Ṣíṣe pẹ̀lú Ọlọ́runÀàrẹ Eyring kọ́ni bí àwọn obìnrin tí wọ́n ti dá májẹ̀mú ṣe nṣiṣẹ́ papọ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run láti sin àwọn ọmọ Rẹ̀ àti báyìí kí wọ́n múrasílẹ̀ láti padà sọ́dọ̀ Rẹ̀. Dallin H. OaksÀwọn Òfin NláMéjì Ààrẹ Oaks ṣàlèyé bí àwọn òfin láti nifẹ Ọlọ́run àti ifẹ́ aladúgbò wa bá ìbáraṣepọ̀ wa pẹ̀lú àwọn wọnnì tí a mọ̀ sí LGBT. Russell M. NelsonÀwọn ìṣura ti Ẹ̀míÀàrẹ Nelson kọ́ni pé àwọn obìnrin tí wọ́n ti gba agbára ẹ̀bùn pẹ̀lú agbára oyèàlùfáà nínú tẹ́mpìlì lè ní ààyè sí agbára Ọlọ́run nínú ayé wọn. Abala Àárọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi Gerrit W. GongWíwà Nínú Májẹ̀múAlàgbà Gong ṣàpèjúwe àwọn ìbùkún ti wíwọnú májẹ̀mú ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run àti pẹ̀lú arawa. Cristina B. FrancoRírí Ayọ̀ nínú Pípín ÌhìnrereArábìnrin franco nkọ́ni ní pàtàkì ṣíṣe àbápín ìhìnrere pẹ̀lú àwọn wọnnì ní àyíká wa. Dieter F. UchtdorfÌgbìdánwò Nlá YínAlàgbà Uchtdorf kọ́ni nípa ìrìnàjò jíjẹ́ ọmọlẹ́hìn wa ó sì gbà wá níyànjú láti wá Ọlọ́run, ṣe iṣẹ́ ìránṣẹ́ sí àwọn ẹlòmíràn, kí a sì ṣe àbápín ìrírí wa pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn. Walter F. GonzálezÌfọwọ́kàni Olùgbàlà Náà.Alàgbà González kọ́ wa pé Olùgbàlà nfẹ́ láti wò wá sàn àti pé tí a bá wá sọ́dọ̀ Rẹ̀ tí a sì nwá ìfẹ́ Rẹ̀, bóyá Òun ó wò wá sàn tàbí fún wa ní okun láti faradà. Gary E. StevensonMáṣe Tàn MíAlàgbà Stevenson kìlọ̀ fún wa nípa árékérekè àti ẹ̀tàn ti ọ̀tá ó sì pè wá láti dúró daindain kí a sì tẹ̀lé àwọn àṣẹ Olúwa. Russell M. NelsonÒfin Ìkejì NláÀàrẹ Nelson fúnni ní àwọn àpẹrẹ bí Ìjọ àti àwọn ọmọ ìjọ ṣe nmú òfin ìkejì nlá Olúwa láti nifẹ àwọn aladugbo wa ní itiraka arannilọ́wọ́. Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsimi Henry B. EyringÌwà Mímọ́ àti Ètò ÌdùnnúÀàrẹ Eyring kọ́ni pé ìdùnnú nwá látinú ìwàmímọ́ araẹni, tí a gbà nípa ìgbàgbọ́ nínú Jésù Krístì, ìrònúpìwàdà, àti dídojúkọ ìpọ́njú. Hans T. BoomMímọ̀, Níní Ìfẹ́, àti DídàgbàAlàgba Boom kọ́ni pé ẹnìkọ̀ọ̀kan wa lè dàgbà nínú ojúṣe wa nínú iṣẹ́ Ọlọ́run nípa wíá láti ọ ẹni tí a jẹ́ àti láti ṣe iṣẹ́ ìránṣẹ́ sí àwọn ẹlòmíràn nínú ìfẹ́ bíiti Krístì. M. Russell BallardFífún Ẹ̀mí Wa Lágbára lórí Ara WaÀàrẹ Ballard kọ́ni pé gbígbé ní yíyẹ gba bíborí ẹlẹ́ran-ara ènìyàn àti fífi ìṣíwájú fún ìwàẹ̀dá ti ẹ̀mí wa. Peter M. JohnsonAgbára láti Borí Ọ̀táAlàgba Jonhson kọ́ni pé a lè borí àwọn ẹ̀tàn Sátánì, ìdàmú, àti àìnírètí nípa àdúrà, ṣiṣé àṣàrò Ìwé ti Mọ́mọ́nì, àti ṣíṣe àbápín oúnjẹ Olúwa. Ulisses SoaresKí A Gbé Àgbélèbú WaAlàgba Soares pè wá láti gbé agbélèbú wa nípa títẹ̀lé apẹrẹ pípé Olùgbàlà ati nípa títẹ̀lé awọn ìkọ́ni ati òfin rẹ̀. Neil L. AndersenÈsoAlàgbà Andersen kọ́ni pé bí a ṣe ndojúkọ Jésù Krístì àti fífi tìgbàgbọ́tìgbàgbọ́ farada àtakò, èso igi ìyè (àwọn ìbùkún Ètùtù) lè jẹ́ tiwa. Russell M. NelsonỌ̀rọ̀ ÌparíÀàrẹ Nelson gba ọmọ ìjọ níyànjú láti di mímọ́ si, láti múrasílẹ̀ fún ìpàdé àpapọ̀ tó nbọ̀, àti láti ṣàṣàrò Ìwé ti Mọ́mọ́nì.