Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Oṣù Kẹ́rin 2022 Abala Òwúrọ̀ Sátidé Abala Òwúrọ̀ Sátidé Russell M. NelsonWíwàásù Ìhìnrere ÀlàáfíàÀàrẹ Nelson kọ́ni pé a gbọ́dọ̀ dúró ní àwọn ibi mímọ́ kí a sì pín ìhìnrere pẹ̀lú gbogbo ayé. M. Russell BallardIṣẹ́ Ìsìn Ìránṣẹ́ Ìhìnrere Bùkún Ayé Mi TítíláéÀàrẹ Ballard kọ́ni nípa àwọn ìbùkun ìṣẹ́-ìsìn iṣẹ́ ìránṣẹ́ ó sì gba àwọn ọ̀dọ́ níyànjú láti múrasílẹ̀ àti láti sin míṣọ̀n ìgbà-kíkún. Reyna I. AburtoÀwa Ni Ìjọ Jésù Krístì ti Àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìnArábìnrin Aburto kọ́ni pé Ìjọ Jésù Krístì ṣe àṣeparí iṣẹ́ rẹ̀ nípasẹ̀ àwọn ọmọ ìjọ rẹ̀. David A. BednarṢùgbọ́n Àwa Kò Kíyèsí Sí Wọn.Alàgbà Bednar kọ́ni bí àwọn májẹ̀mú àti ìlànà yíò ṣe rànwá lọ́wọ́ nílọsíwájú lẹgbẹ́ ipa-ọ̀nà májẹ́mú kí a má sì “gbọ́ ohun” tí àwọn ẹlòmíràn nsọ. Neil L. AndersenTítẹ̀lé Jésù: Jíjẹ́ Onílàjà kanAlàgbà Andersen ṣe àlàyé bí a ti lè borí ìjà pẹ̀lú ìgbàgbọ́ nínú Jésù Krístì. Eduardo GavarretÌyípadà Ọkàn Nlá; Èmi Kò Ní Ohunkóhun Síi Láti Fún ỌAlàgbà Gavarret kọ́ni bí a ṣe lè gbà, damọ̀, àti mú ìyípadà ọkàn dúró. Larry S. KacherÀkàbà Ìgbàgbọ́Alàgbà Kacher kọ́ni pé ìgbàgbọ́ wa nínú Jésù Krístì lè ṣí àwọn agbára ọ̀run sílẹ̀ kí ó sì fún wa lókun bí a ṣe ndojú kọ àwọn ìpèníjà ìgbésí ayé. Henry B. EyringDíduróṣinṣin nínú àwọn ÌjìÀàrẹ Eyring kọ́ni pé a lè dúróṣinṣin nínú àwọn ìjì ayé nípa gbígbáralé Olùgbàlà ní dídà bí ọmọ kan. Abala Ọ̀sán Sátidé Abala Ọ̀sán Sátidé Dallin H. OaksÌmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè GbogbogbòÀàrẹ Oaks ṣè àgbékalẹ̀ àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè Gbogbogbò kalẹ̀ fún ìbò ìmúdúró. Jared B. LarsonÌròhìn Ẹ̀ka Jíjẹ́rí Ìṣírò Ohun-ìní Ìjọ, Ọdún 2021Jared B. Larson gbé ìròhìn Ẹ̀ká ìjẹ́ri Ìṣirò Ohun-ìní Ìjọ fún 2021 kalẹ̀. Jeffrey R. HollandMá Bẹ̀rù: Gbàgbọ́ Nìkan!Alàgbà Holland kọ́ni pé a lè ní ìrètí ní àwọn àkokò ìṣòro nítorí ìhìnrere ti Jésù Krístì. Patrick KearonÓ jínde Pẹ̀lú Ìwòsàn Ní Ìyẹ́ Apá Rẹ̀: A Lè Ju Aṣẹ́gun LọAlàgbà Kearon kọ́ni pé àwọn tó yọ nínú ewu ìlòkulò kò jẹ̀bi ìlòkulò wọ́n sì lè wá ẹ̀bùn ìwòsàn ti Olùgbàlà. Marcos A. AidukaitisGbé Ọkàn Rẹ Sókè Kí O sì Yọ̀Alàgbà Aidukaitis kọ́ àwọn ọ̀dọ́ pé Ọlọ́run yíò bùkún wọn lọ́pọ̀lọpọ̀ bí wọ́n ṣe nborí àwọn ìbẹ̀rù àti àìláàbò tí wọ́n sì nsìn Ín gẹ́gẹ́bí òjíṣẹ́ ìhìnrere ìgbà kíkún. Gerrit W. GongẸnìkọ̀ọ̀kan Wa Ní Ìtàn kanAlàgbà Gong pé wá láti wá ìsopọ̀ àti wíwà-pẹ̀lú nínú ẹbí Ọlọ́run nípasẹ̀ àkọọ́lẹ̀-ìtàn ẹbí wa. Adrián OchoaṢé Ètò Náà Nṣiṣẹ́Alàgbà Ochoa kọ́ni ní àwọn ẹ̀kọ́-ìpìnlẹ̀ mẹ́ta láti ran ẹnikẹ́ni tí ó bá ní ìmọ̀lára pé ètò ìdùnnú kìí ṣiṣẹ́ nínú ìgbé-ayé wọn. Kevin S. Hamilton“Nígbànáà Ni Èmi ó Sọ Àwọn Ohun Aláìlágbára Di Alágbára”Alàgbà Hamilton kọ́ni pé ìrònúpìwàdà ṣe dandan àti pé bí a bá ti rẹ ara wa sílẹ̀ tí a sì ní ìgbàgbọ́ nínú Jésù Krístì, àwọn àìlágbára wa le jẹ́ sísọ di alágbára nípasẹ̀ oore ọ̀fẹ́ Krístì. Quentin L. CookÌyípadà sí Ifẹ́ Ọlọ́runAlàgbà Cook kọ́ni pé ìyípadà wà pẹ̀lú títẹ́wọ́gba ìfẹ́ Ọlọ́run, fífún ẹ̀rí wa nípa Ìmúpadàbọ̀sípò lókun, àti pípín àwọn ìbùkún ìhìnrere. Abala ti Àwọn Obìnrin Abala ti Àwọn Obìnrin Dallin H. OaksỌ̀rọ̀ ÌṣaájúÀàrẹ Oaks ṣàfihàn ìgbà pàtàkì yii tí àpéjọpọ̀ gbogbogbò ti dojúkọ àwọn àníyàn ti àwọn obìnrin àti àwọn ẹgbẹ́ wọn. Susan H. PorterÀwọn Ẹ̀kọ́ Látinú KàngaArábìnrin Porter pín àwọn ẹ̀kọ́ mẹ́ta tí ó nkọ́ ó sì pe àwọn obìnrin Ìjọ láti tẹ̀lé àwọn ìkọ́ni Olùgbàlà láti jẹ́ iyọ̀, ìmọ́lẹ̀, àti ìwú. Rebecca L. CravenṢe Ohun Tó Ṣe Pàtàkì JùlọArábìnrin Craven kọ́ni pé bí a ṣe ntiraka láti dojúkọ ohun tó ṣe pàtàkì jùlọ, ìbáṣepọ̀ wa pẹ̀lú Ọlọ́run á lókun si. Fídíò: “Ẹ̀yin ni Àwọn Obìnrin tí Ó Rí Ṣíwájú”Fídíò: “Ẹ̀yin ni Àwọn Obìnrin tí Ó Rí Ṣíwájú”Fídíò yí ní àwọn ìkọ́ni nípa àwọn obìnrin nínú láti ẹnu Ààrẹ Nelson àti Ààrẹ Kimball. Jean B. BinghamǍwọn Májẹ̀mú pẹ̀lú Ọlọ́run Nfúnni Lókun, Ndáàbò bò, ó sì Nmúra Wa sílẹ̀ fún Ògo Ayérayé.Ààrẹ Bingham kọ́ni pé dídá àti pípa àwọn májẹ̀mú pẹ̀lú Ọlọ́run mọ́ nmú ìdùnnú wá fúnwa àti ààbò nísisìyí àti ayọ̀ ayérayé ní ayé tí nbọ̀. Dale G. RenlundÌwà-ẹ̀dá Àtọ̀runwá àti Ípin Ayérayé YínAlàgbà Relund lo Àkórí àwọn Ọ̀dọ́mọbìnrin láti kọ́ nípa ìwà-ẹ̀dá àtọ̀runwá àti ìpín ayérayé wa. Abala Àárọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi Abala Àárọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi D. Todd ChristoffersonÌbáṣepọ̀ Wa Pẹ̀lú Ọlọ́runAlàgbà Christofferson kọ́ni pé ohunkóhun tí àwọn ipò ara kíkú wa le jẹ́, a le ní ìgbẹ̀kẹ̀lé pé Ọlọ́run yío mú àwọn ìlérí Rẹ̀ ṣẹ. Amy A. WrightJésù Nṣe Ìwòsàn Èyíinì Tí O ti Fọ́Arábìnrin Wright kọ́ni pé kò sí ohunkóhun nínú ìgbé ayé yín tí ó ti bàjẹ́ tí ó kọjá agbára títúnṣe, ríràpadà, àti agbára alèṣe ti Jésù Krístì. Gary E. StevensonFẹ́, Pín, PèAlàgbà Stevenson kọ́ni ní àwọn ohun ìrọ̀rùn mẹ́ta tí gbogbo wa lè ṣe láti pín ìhìnrere: fẹ́, pín, àti pè. Ní ṣíṣe bẹ́ẹ̀, à nṣèrànwọ́ láti mú àṣẹ Olùgbàlà ṣẹ láti “kọ́ gbogbo orílẹ̀-èdè.” Michael T. RingwoodNítorí Ọlọ́run Fẹ́ Wa Tó Bẹ́ẹ̀ Gẹ́Alàgbà Ringwood kọ́ni bí Baba Ọ̀run ṣe rán Ọmọ Rẹ̀, Jésù Krístì, gẹ́gẹ́bí ara ètò Rẹ̀ láti ràn wá lọ́wọ́ láti padà sọ́dọ̀ Rẹ̀. Ronald A. RasbandLáti Wo Ayé SànAlàgbà Rasband kọ́ni ní àwọn ọ̀nà mẹrin tí àwùjọ àti àwọn ẹnìkọ̀ọ̀kan fi njèrè látinú òmìnira ẹ̀sìn àti bí òmìnira fi lè jẹ́ ipa rírẹ́pọ̀ àti wíwòsàn. Hugo E. MartinezKíkọ́ Ìgbẹ́kẹ̀lé-araẹni sí Àwọn Ọmọdé àti Ọ̀dọ́Alàgbà Martinez ṣe àlàyé a`àwọn ìbùkún tí ó nwá látinú gbígbé ìgbé-ayé àwọn ẹ̀kọ́-ìpìlẹ̀ ìgbẹ́kẹ̀lé ara-ẹni àtí kíkópa nínú ètò àwọn Ọmọdé àti Ọ̀dọ́. Russell M. NelsonAgbára Ipa Ti-Ẹ̀míÀàrẹ Nelson ṣàjọpín ọ̀nà marun tí a fi lè dá ipa ti-ẹ̀mí sílẹ̀, dá àti pa àwọn májẹ̀mú mọ́, ronúpìwàdà, kọ́ nípa Ọlọ́run, wá àwọn iṣẹ́ ìyanu, àti láti parí ìjà. Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsimi Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsimi Dallin H. OaksÌfẹ́ Àtọ̀runwá nínú Ètò Bàbá.Ààrẹ Oaks kọ́ni pé ètò ìgbàlà jẹ́ ìpìlẹ̀ lórí ìfẹ́ Bàbá Ọ̀run fún wa. Adeyinka A. OjediranIpa Ọ̀nà Májẹ̀mú: Ọ̀nà sí Ìyè AyérayéAlàgbà Ojediran kọ́ni pé à nwá sọ́dọ̀ Krístì nípasẹ̀ àwọn májẹ̀mú, ó sì ṣe àlàyé bí Ẹ̀mí Mímọ́ àti oúnjẹ Olúwa fi lè rànwálọ́wọ́ láti pa àwọn májẹ̀mú wọnnì mọ́ Jörg KlebingatJíjẹ́-Ọmọlẹ́hìn Alágbára ní Àwọn Ọjọ́ ÌkẹhìnAlagba Klebingat kọ́ni nípa bí a ṣè lè jẹ́ ọmọẹ̀hìn alágbára ti Jésù Krístì. Mark L. PaceÌyípadà Ni Ìlépa WaÀàrẹ Pace kọ́ni ní àwọn ìbùkún tí ó nwá látinú fífietísílẹ̀ sí Ẹ̀mí Mímọ́ àti jíjẹ́ yíyípadà sí ìhìnrere Jésù Krístì. Ulisses SoaresNínú Ìyanu Krístì àti Ìhìnrere Rẹ̀Alàgbà Soares kọ́ni pé nígbàtí a bá wà nínú ọ̀wọ̀ fún Jésù Krístì nítòótọ́, a máa nláyọ̀ síi, a nní ìtara púpọ̀ síi fún iṣẹ́ Ọlọrun, a sì ndá ọwọ́ Olúwa mọ̀ nínú ohun gbogbo. Alàgbà Randy D. FunkWá sínú Agbo Ọlọ́runAlàgbà Fúnk jẹ́ri nípa àwọn ìbùkún tí ó nwá sí ọ̀dọ̀ àwọn tí wọ́n bá yàn láti wá sínú Agbo Ọlọ́run nípa gbígbọ́ràn sí ìhìnrere ti Jésù Krístì. Dieter F. UchtdorfÀtọkànwá Wa GbogboAlàgbà Uchtdorf kọ́ni pé a le fi gbogbo ọkàn wa fún Olùgbàlà nípasẹ̀ irúbọ àti ìyàsọ́tọ̀. Russell M. NelsonÌsisìyí Ni Wákàtí NáàÀàrẹ Nelson kọ́ni pé ìsisìyí ni àkókò láti gbé ìgbé ayé ìhìnrere ti Jésù Krístì.