Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Oṣù Kẹwa 2022 Abala Òwúrọ̀ Sátidé Abala Òwúrọ̀ Sátidé Dallin H. OaksṢíṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Tálákà àti Olùpọ́njúÀàrẹ Oaks kọ́ni pé Ọlọ́run nmísí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìṣétó àti ẹnìkọ̀ọ̀kan láti ran àwọn wọnnì nínú àìní lọ́wọ́ àti pé Ìjọ nifẹ láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn nínú i`tiraka náà. Dieter F. UchtdorfJésù Krístì Ni Okun Àwọn Ọ̀dọ́Alàgbà Uchtdorf kọ́ni pé Jésù Krístì ni atọ́nà tó dára jùlọ fún siṣe àwọn yíyàn. Bákannáà ó ṣe àfihàn àtọ́nà sí Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ titun. Tracy Y. BrowningRírí Jésù Krístì Síi nínú Àwọn Ìgbésí Ayé WaArábìnrin Browning gba wá níyànjú láti rí ìgbé ayé wa nínú ìwò ìhìnrere ní èrò láti rí Olùgbàlà síi nínú ayé wa. Dale G. RenlundÌlànà Kan fún Ìfihàn AraẹniAlàgbà Renlund kọ́ni bí a ti lè gba ìfihàn araẹni nípasẹ̀ Ẹ̀mí Mímọ́ àti bí a ó ti yẹra fún ẹ̀tàn. Rafael E. PinoJẹ́kí Ṣíṣe Rere Jẹ́ Títọ́ WaAlàgbà Pino daba ìwà mẹ́rin láti ran àwọn ọmọ Ìjọ lọ́wọ́ láti dúró lórí ipa ọ̀nà májẹ̀mú. Hugo MontoyaẸ̀kọ Ìpìlẹ̀ Ayérayé ti Ìfẹ́ Alàgbà Montoya kọ́ni ní pàtàkì fífẹ́ràn Ọlọ́run àti ṣíṣe iṣẹ́ ìránṣẹ́ sí a`wọn wọnnì ní àyíka wa. Ronald A. RasbandÒni´ YíAlàgbà Rasband fúnni ní àpẹrẹ Ààrẹ Nelson tí ó npín Ìwé ti Mọ́mọ́nì, ó júwe bí òun ti gbìyànjú láti tẹ̀lé àpẹrẹ wòlíì náà, ó sì pe gbogbo ènìyàn láti ṣe bákannáà. Russell M. NelsonKíni Ó Jẹ́ Òtítọ́?Ààrẹ Nelson tẹnumọ́ àwọn ìkọ́ni nípa ìlòkulò ó sì jẹ́ ẹ̀rí pé Ọlọ́run ni orísun gbogbo òtítọ́. Abala Ọ̀sán Sátidé Abala Ọ̀sán Sátidé Henry B. EyringÌmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè Gbogbogbò M. Russell BallardTẹ̀lé Jésù Krístì pẹ̀lú Àwọn Ìṣísẹ̀ Ìgbàgbọ́Ààrẹ Ballard kọ́ni pé bí a ti ntẹ̀lé Jésù Krístì nínú ìgbàgbọ́, Òun yío rànwá lọ́wọ́ nínú àwọn àkókò ìṣòro, gẹ́gẹ́bí Ó ti ṣe sí àwọn aṣaájú. Kristin M. YeeẸwà fún Eérú: Ipa Ọnà Iwòsàn ti ÌdáríjìArábìnrin Yee kọ́ni pé a di alábùkún bí a ti ntẹ̀lé Olùgbàlà ní ipá ọ̀nà ìwòsàn sí ìdáríjì. Paul V. JohnsonJẹ́ Pípé Nínú Rẹ̀Alàgbà Johnson kọ́ni pé nípasẹ̀ Ètùtù Jésù Krístì gbogbo wa lè gba ìwẹ̀nùmọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ àti àìpé wa kí a sì wòsàn. Ulisses SoaresNínú Àjọṣepọ̀ pẹ̀lú OlúwaAlàgbà Soares kọ́ni pé bí àwọn obìnrin àti àwọn ọkùnrin ti nṣiṣẹ́ papọ̀ ní àwọn ìbáṣepọ̀ tòótọ́ àti dídọ́gba, wọn ó gbádùn ìṣọ̀kan tí Olùgbàlà kọ́ni. James W. McConkie IIIWọ́n Sì Lépa láti Rí Ẹni Tí Jésù Í ṢeAlàgbà McConkie kọ́ni nípa pàtàkì kíkọ́ ẹ̀kọ́ nípa Jésù Krístì àti ríran àwọn ẹlòmíràn lọ́wọ́ láti wá sí ọ̀dọ̀ Rẹ̀. Jorge F. ZeballosSíṣe Ẹ̀dá Ìgbé Ayé kan Tí ó ní Àtakò sí ỌtáAlàgbà Zeballos kọ́ni pé pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ Olúwa, a lè di kíkọ̀ sí ẹ̀ṣẹ̀ àti àdánwò kí a sì rí ìdùnnú pípé nínú ayé yí. D. Todd ChristoffersonẸ̀kọ́ ti Jíjẹ́ Ara KannáàAlàgbà Christofferson kọ́ni pé nínú ẹ̀kọ́ ti Jíjẹ́ Ara Kannáà ni oríṣi ìkíni káàbọ̀, síṣetán láti sìn àti láti rúbọ, àti mímọ ipa Olùgbàlà wà. Abala Ìrọ̀lẹ́ Sátidé Abala Ìrọ̀lẹ́ Sátidé Gérald CausséIṣẹ́ Ìríjú Wa ti Ilẹ̀ AyéBíṣọ́pù Caussé kọ́ni ní ojúṣe tí a ní láti tọ́jú àwọn ìṣẹ̀dá ọlọ́run bí olùtọ́jú lórí wọn. Michelle D. CraigTọkàn-tọkànArábìnrin Craig kọ́ wa ní àwọn òtítọ́ mẹ́ta tí ó lè ràn wá lọ́wọ́ láti dàgbà bí àwọn ọmọ-ẹ̀hìn kí a sì gbẹ́kẹ̀lé Olúwa nípasẹ̀ àwọn àdánwò wa. Kevin W. PearsonṢé O Ṣì Nfẹ́Alàgbà Pearson kọ́ni pé Ọlọ́run nretí pé kí a fi tìfẹ́tìfẹ́ gbé Olùgbàlà sí àárín gbùngbùn ìgbésí ayé wa. Denelson SilvaÌgboyà láti Kéde Òtítọ́Alàgbà Silva ṣe àpèjúwa ìrírí ìyípada rẹ̀ àti gbígba a`wọn ọ̀dọ́mọkùnrin a`ti ọ̀dọ́mọbìnrin níyànjú láti sìn ní míṣọ̀n. Neil L. AndersenSísúnmọ́ Olùgbàlà SíiAlàgbà Andersen kọ́ni pé a le múrasílẹ̀ fún Bíbọ̀ Èkejì nípa dídá àwọn májẹ̀mú àti fífi okun fún ìfọkànsìn wa sí Olùgbàlà. Abala Àárọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi Abala Àárọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi Jeffrey R. HollandA Gbé e Sókè lórí ÀgbélèbúAlàgbà Holland kọ́ni ní ohun tó tùmọ̀ sí láti gbé àgbélébú bí àwọn ọmọ-ẹ̀hìn Jésù Krístì. J. Anette DennisÀjàgà Rẹ̀ Rọrùn Ẹrù Rẹ̀ sì Fúyẹ́Arábìnrin Dennis kọ́ni pé a níláti yẹra fún dídá àwọn ẹlòmíràn lẹ́jọ́ àti dípò bẹ́ẹ̀ kí a jẹ́ alãnú àti olùfẹ́ni sí ẹni gbogbo. Gerrit W. GongIdùnnú àti TítíláéAlàgbà Gong kọ́ni pé bí a ti ntẹ̀lé ètò Ọlọ́run fún wa, a ó rí ayọ̀ ayérayé pẹ̀lú àwọn ẹbí wa. Joseph W. SitatiÀwọn Àwòṣe ti Jíjẹ́ Ọmọ-ẹ́hìnAlàgbà Sitati kọ́ni bí a ṣe lè mú àwọn ìwà tí ó ràn wá lọ́wọ́ láti di ọmọlẹ́hìn Kristi dàgbà. Steven J. LundJíjẹ́ Ọmọ-ẹ̀hìn TítíláéÀàrẹ Lund ṣe àpèjúwe okun ti ẹ̀mí tí ó nwá látinú àwọn ìpàdé àpapọ̀ FSY ti´ ó sì nkọ́ àwọn ọ̀dọ́ bí wọ́n ti lè mú okun wọn dúró. David A. BednarGbé Agbára Rẹ Wọ̀, Áà SíónìAlàgbà Bednar lo òwe ti àpèjẹ ìgbeyàwó ọlọ́ba láti kọ́ni pé, nípasẹ̀ lílo ìwà agbára òmìnira láti yàn wa pẹ̀lú òdodo, a le yàn láti jẹ́ yíyàn láti ọwọ́ Olúwa. Russell M. NelsonẸ Ṣẹ́gun Ayé kí ẹ sì Wá ÌsinmiÀàrẹ Nelson jẹri pé a lè ṣẹ́gun ayé kí a sì wá ìsinmi, nípa agbára Jésù Krístì, èyí tì à nní ààyè sí nípasẹ̀ àwọn májẹ̀mú wa. Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsimi Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsimi Henry B. EyringOgún Ìgbani-níyànjúÀàrẹ Eyring fihàn bí ìyá rẹ̀ àti wòlíì Mọ́mọ́nì ti gba àtẹ̀lé wọn níyànjú láti yege fún ìyè ayérayé nínú gbogbo àwọn àdánwò ayé ikú. Ryan K. OlsenÌdáhùn Náà Ni JésùAlàgbà Olsen kọ́ni pé ìdáhùn sí àwọn ìpèníjà àti àwọn ìbéèrè wa ni Jésù Krístì. Jonathan S. SchmittKí Wọ́n Lè Mọ̀ YínAlàgbà Schmitt kọ́ wa pé kíkọ́ ẹ̀kọ́ nípa àwọn orúkọ púpọ̀ Jésù le mí sí wa láti dà bíi Rẹ̀ síi? Mark D. EddyÌwà Rere ti Ọ̀rọ̀ náàAlàgbà Eddy pè wá láti “gbìyànjú ìwà rere ọ̀rọ̀ Ọlọ́run” kí a sì “mu jinlẹ̀” láti inú awọn ìwé mímọ́. Gary E. StevensonṢíṣìkẹ́ àti Jíjẹ́ Ẹ̀rí YínAlàgbà Stevenson kọ́ni nípa ohun tí ẹ̀rí jẹ́ àti pàtàkì pípa ẹ̀rí yín mọ́ nínú agbára àti jijẹri rẹ̀ ní ọ̀rọ̀ àti ìṣe. Isaac K. MorrisonA Lè Ṣe Àwọn Ohun Líle Nípasẹ̀ Rẹ̀Alàgbà Morrison kọ́ wa bí Olúwa ti máa nfún wa lókun tí Ó sì nrànwá lọ́wọ́ nígbàtí a bá lo ìgbàgbọ́ nínú Rẹ̀ ní àwọn àkókò ìṣòro Quentin L. CookJẹ́ Olõtọ sí Ọlọ́run àti Iṣẹ̀ Rẹ̀Alàgbà Cook kọ́ni nípa jíjẹ́ pàtàkì ti gbígba àwọn ẹ̀rí ti ara wa nípa Jésù Krístì, ríronúpìwàdà àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, àti jíjẹ́ olõtọ́ sí Ọlọ́run àti iṣẹ́ Rẹ̀ Russell M. NelsonNí Ìdojúkọ Sí Tẹ́mpìlìÀàrẹ Nelson kọ̀ni nípa pàtàkì àwọn tẹ́mpìlì ó sì kéde àwọn ètò láti kọ́ àwọn tẹ́mpìlì titun síi.