Ìpàdé àpapọ̀ gbogbogbò Oṣù Kẹ́wàá 2023 Abala Òwúrọ̀ Sátidé Abala Òwúrọ̀ Sátidé David A. BednarNí Ipa Ọnà ti Ojúṣe WọnAlàgbà Bednar fi ìmoore rẹ̀ hàn fún àwọn ọmọ Ìjọ tí wọ́n nsìn jákèjádò àgbáyé tí wọ́n sì jẹ́ agbára ti Ìjọ. Amy A. WrightGbé Ọjọ́ náà nínú KrístìArábìnrin Wright kọ́ni pé pẹ̀lúìrànlọ́wọ́ Jésù Krístì, gbogbo wa lè “gbé ọjọ́ náà” kí a sí pàdé kí a sì borí àwọn ìpènijà tí à nkojú. Robert M. DainesAlàgbà, Awa Fẹ́ Rí JésùAlàgbà Daines kọ́ni ní àwọn ẹ̀kọ́-ìpìlẹ̀ mẹ́rin láti ràn wá lọ́wọ́ láti rí Olùgbàlà kí a sì ní òye ìfẹ́ Ọlọ́run. Carlos A. GodoyNítorí Ìrandíran YínAlàgbà Godoy béèrè lọ́wọ́ àwọn tí wọ́n ti ṣubú tàbí tí wọn kìí ṣe olootọ bí ó ti yẹ kí wọ́n yípadà kí àwọn àti ìrandíran wọn lè gbádùn àwọn ìbùkún ìhìnrere. D. Todd ChristoffersonAgbára ÈdidìAlàgbà Christofferson kọ́ni pé agbára ìfi èdidì dì, èyí tí ó nfi àṣẹ fún gbogbo àwọn ìlànà oyè-àlùfáà tí ó sì nmú wọn ní ìsopọ̀ lórí ilẹ̀ ayé àti ní ọ̀run, jẹ́ kókó fún kíkójọ Israel. Ian S. ArdernFẹ́ Ọmọnìkejì RẹAlàgbà Ardern kọ́ni pé àwọn ìtiraka ìrannilọ́wọ́ jẹ àwọn ọ̀nà láti fi ìyọ́nú hàn sí àwọn ẹlòmíràn àti láti tẹ̀lé àṣẹ Olúwa láti “fẹ́ ọmọnìkejì rẹ.” Dallin H. OaksÀwọn Ìjọba OlógoÀàrẹ Oaks kọ́ni nípa àwọn ìjọba ológo lẹ́hìn ayé yí àti ìfojúsùn Ìjọ lórí ríràn wá lọ́wọ́ láti yege fún ìpele gígajùlọ ti ìjọba Sẹ̀lẹ́stíal. Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Sátidé Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Sátidé Henry B. EyringÌmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè GbogbogbòÀàrẹ Eyring ṣè gbé kalẹ̀ àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè Gbogbogbò fún ìbò ìmúdúró. Neil L. AndersenṢíṣí àwọn Fèrèsé Ọ̀runAlàgbà Andersen kọ́ni pé bí a ti nsan idamẹwa wa pẹ̀lú òtítọ́, Olúwa yíò ṣí àwọn fèrèsé ọ̀run láti tú àwọn ìbùkún jáde lé wa lórí. Jan E. NewmanPípa Ohùn Àwọn Ènìyàn Májẹ̀mú Mọ́ nínú Ìran tí ó NdìdeArákùnrin Newman kọ́ni pé ó jẹ́ ojúṣe àwọn òbí láti kọ́ àwọn ọmọ wọn láti wá sí ọ̀dọ̀ Jésù Krístì. Joaquin E. CostaAgbára Jésù Krístì nínú Ayé Wa Lójoojúmọ́Mo ti ríi pé orísun okun náà ni ìgbàgbọ́ nínú Jésù Krístì bí a ti nlépa láti wá sí ọ̀dọ̀ Rẹ̀ lọ́jọ́ kọ̀ọ̀kan àti ojoojúmọ́. Gary E. StevensonÀwọn Ìṣílétí Ẹ̀míAlàgbà Stevenson kọ́ni ní pàtàkì wíwá, dídámọ̀, àti ṣíṣe ìṣe lórí àwọn ìṣílétí Ẹ̀mí Mímọ́. Yoon Hwan ChoiNjẹ́ Ẹ Fẹ́ Ní Ìdùnnú?Alàgbà Choi kọ́ni pé bí a bá fẹ́ láti ní ìdùnnú, a níláti dúró ní ipá-ọ̀nà májẹ̀mú. Olúwa yíò bùkún wa yíò sì gbé àjàgà wa. Alan T. PhillipsỌlọ́run mọ̀ Ó sì fẹ́ràn yín.Alàgbà Phillips kọ́ni pé ọmọ Ọlọ́run ni wá, pé Jésù Krístì ràwá padà, ó sì mú ìtura wá, àti pé Baba Ọ̀run jẹ́ pípé àti olùfẹni. Ronald A. RasbandBí Ayọ̀ Yín Ó Ti Pọ̀ TóAlàgbà Rasband kọ́ni pé láti kó Ísráẹ́lì jọ, a nílò àwọn òjíṣẹ́ ìhìnrere a sì pe àwọn àgbà láti mú ìmọ̀ àti ẹ̀rí wọn kí wọ́n sì lọ ṣe íṣẹ́-ìránṣẹ́. Abala Ìrọ̀lẹ́ Sátidé Abala Ìrọ̀lẹ́ Sátidé Gary B. SabinÀwọn Àmì Ìyàsọ́tọ̀ ti ÌdùnnúAlàgbà Sabin kọ́ni ní àwọn ọ̀nà marun láti rí ìdùnnú òtítọ́. Joni L. KochNírẹ̀lẹ̀ láti Gbà àti Láti Tẹ̀leAlàgbà Koch kọ́ni ní pàtàkì jíjẹ́ onírẹ̀lẹ̀ àti níní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Olúwa. Tamara W. RuniaRírí Ẹbí ti Ọlọ́run láti inú Jígí Àkópọ̀Arábìnrin Runia kọ́ni pé agbára àti ayọ̀ wà nígbàtí a bá yẹ arawa àti àwọn olólùfẹ́ wa wo látinú ojú-ìwòye àwòrán-nlá. Ulisses SoaresẸ̀yin Arákùnrin àti Arábìnrin nínú KrístìAlàgbà Soares kọ́ni bí a ó ti tọ́nisọ́nà ní àtakò sí ẹ̀tanú kí a sì tọjú ara wa bí arákùnrin àti arábìnrin nínú Jésù Krístì. Abala Òwúrọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi Abala Òwúrọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi M. Russell BallardÌyìn fún Ọkùnrin NáàÀàrẹ Ballard jẹ́ ẹ̀rí nípa ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìbùkún tí a ngbádùn nítori ti Wòlíì Joseph Smith, ẹni tí ó mú ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìhìnrere ti Jésù Krístì padàbọ̀sípò. Emily Belle FreemanRírìn nínú Ìbáṣepọ̀ Májẹ̀mú pẹ̀lú KrístìÀàrẹ Freeman ṣe àfiwé rírìn ní ipa ọ̀nà májẹ̀mú pẹ̀lú rírìn Ipa Ọnà Ẹsẹ̀ ti Jésù ní Isráẹ́lì. Adilson de Paula ParrellaJíjẹ́ Ẹ̀rí nípa Jésù Krístì nínú Ọ̀rọ̀ àti Àwọn ÌṣeAlàgbà Parrella kọ́ni pé a lè mú orúkọ Olùgbàlà wá sórí wa nípa jíjẹ́ ẹ̀rí nípa Rẹ̀ nípasẹ̀ àwọn ọ̀rọ̀ àti ìṣe wa. Quentin L. CookẸ Jẹ́ Àwọn Àtẹ̀lé Oníwàpẹ̀lẹ́ ti KrístìAlàgbà Cook kọ́ni pé àwọn àtẹ̀lé oníwàpẹ̀lẹ́ ti Krístì tí wọ́n pa àwọn òfin Rẹ̀ mọ́ yíò di alábùkún pẹ̀lú àláfíà bí wọ́n ti nkojú àwọn àdánwò wọn tí wọ́n sì lè wo iwájú sí ọjọ́-ọ̀la dídán. Dieter F. UchtdorfOninakuna àti Ọ̀nà Tí Ó Darí SíléDieter F. Uchtdorf kọ́ni pé kò pẹ́ jù rárá láti ronúpìwàdà àti láti padà sí ipa ọ̀nà tí ó darí sí ọ̀dọ̀ Ọlọ́run. W. Christoper WaddellJu Akọni Kan LọBíṣọ́ọ̀pù Waddell kọ́ni pé nínú gbogbo àwọn akọni, Jésù Krístì ni ó tóbijùlọ. Henry B. EyringAlábàárìn Wa Ní Gbogbo ÌgbàÀàrẹ Eyring kọ́ni pé a nílò láti tiraka láti ní Ẹ̀mí Mímọ́ bí alabarin ìgbàgbogbo wa. Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsinmi Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsinmi John C. Pingree Jr.Òtítọ́ AyérayéAlàgbà Pingree ṣe àlàyé ohun tí òtítọ́ jẹ́, ìdí tí ó fi ṣe pàtàkì, bí a ti le rí i, àti bí a ṣe níláti pín in pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn. Dale G. RenlundJésù Krístì Ni ÌṣuraAlàgbà Relund kọ́ni pé bí a ti nfojúsùn lórí Jésù Krístì tí a sì dáwọ́dúró ní wíwò kọ̀ja àmì, a ó rí àwọn ìṣúra títóbíjùlọ ti ìhìnrere. Valeri V. CordónÀwọn Ẹ̀kọ́ ti Ọ̀run Fún Ṣíṣe ÒbíAlàgbà Cordón kọ́ni pé àwọn òbí gbọ́dọ̀ kọ́ àwọn ọmọ wọn ní ọ̀làjú ìhìnrere kí wọ́n sì ṣèrànwọ́ láti tọ́ wọn sọ́nà padà sí ọ̀run. J. Kimo EsplinAgbára Ìwòsàn Olùgbàlà lórí Erékùṣù ÒkunAlàgbà Esplin pín ìtàn kan nípa Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn Ará Japan kan tí ó e ìjúwe agbára tí a lè rí nínú àwọn májẹ̀mú tẹ́mpìlì. Gerrit W. GongÌfẹ́ Ni À Nsọ̀rọ̀ Rẹ̀ NihinAlàgbà Gong kọ́ni bí a ti lè lo àwọn èdè ìhìnrere mẹ́ta: ìyárí àti ọ̀wọ̀, iṣẹ́-ìsìn àti ìrúbọ̀, àti wíwà nínú májẹ̀mú. Christophe G. Giraud-CarrierÀwa ni Ọmọ Rẹ̀.Alàgbà Giraud-Carrier kọ́ni pé a nílati rántí pé gbogbo wa jẹ́ ọmọ Ọlọ́run a sì níláti fẹ́ran gbogbo ènìyàn, láìka àwọn ìyàtọ̀ wa sí. Russell M. NelsonRonú Sẹ̀lẹ́stíà!Ààrẹ Nelson kọ́ni ní pàtàkì níní ìgbàgbọ́ nínú Jésù Krístì àti ṣíṣe àwọn àṣàyàn pẹ̀lú ìjọba sẹ̀lẹ́stíà nínú.