Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Oṣù Kẹ́rin 2024 Abala Òwúrọ̀ Sátidé Abala Òwúrọ̀ SátidéAbala Òwúrọ̀ Sátidé ti Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Ọlọ́dọdún Ìkẹrìnléláàdọ́wàá ti Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn tí a ṣe ní Ọjọ́ Ìkẹfà sí ìkéje Oṣù Kẹrin, 2024. Dallin H. OaksÌmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè GbogbogbòÀàrẹ Oaks ṣè àgbékalẹ̀ àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè Gbogbogbò kalẹ̀ fún ìbò ìmúdúró. Jared B. LarsonÌròhìn Ẹ̀ka Jíjẹ́rí Ìṣírò owó Ìjọ, Ọdún 2023Jared B. Larson ka jíjẹ́rí ìṣiro owó Ìjọ. Jeffrey R. HollandÀwọn Ìbìlù Iná Tó-FarasinÀàrẹ Holland kọ́ni nípa agbára àdúrà ó sì jẹ́ri pé Ọlọ́run ndáhùn gbogbo àdúrà. J. Anette DennisẸ Gbé Jésù Krístì Olúwa Wọ̀Arábìnrin Dennis kọ́ni nípa pàtàkì, agbára, ati awọn ìbùkún ti dídá ati pípa awọn májẹ̀mú mọ́ pẹ̀lú Ọlọ́run. Alexander DushkuÀwọn Òpó àti ÌtànṣánAlàgbà Dushku kọ́ wa pé àwọn ìrírí ti ẹ̀mí àgbàyanu ṣọ̀wọ́n àti pé Olúwa sábà máa nfún wa ní ìtànṣán ìmọ́lẹ̀ kan ní àkókò kan. Ulisses SoaresMájẹ̀mú Ìgbẹ́kẹ̀lé nípasẹ̀ Jésù KrístìAlàgbà Soares kọ́ni nípa pàtàkì gbígbé nípasẹ̀ àwọn májẹ̀mú tí a ti dá, èyí tí ó nfún wa lókun àti ìgbẹ́kẹ̀lé. Jack N. GerardÌwà-títọ́: Ìhùwàsí Bíi-ti-KrístìAlàgbà Gerald kọ́ pé gbígbé ìgbésí ayé ìwà-títọ́ nbéèrè pé kí a jẹ́ olotọ sí Ọlọ́run, sí ara wa, àti sí ìdánimọ̀ àtọ̀runwá wa. Henry B. EyringGbogbo Rẹ̀ Ó Dára Nítorí àwọn Májẹ̀mú Tẹ́mpìlìÀàrẹ Eyring kọ́ni pé bí a ti ndá tí a sì npa àwọn májẹ̀mú tẹ́mpìlì mọ́, a ó gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìbùkún ti-ẹ̀mí, nísisìyí àti ní àìlópin pẹ̀lú. Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Sátidé Abala Ọ̀sán Ọjọ́ SátidéAbala Ọ̀sán Sátidé ti Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Ọlọ́dọdún Ìkẹrìnléláàdọ́wàá ti Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn tí a ṣe ní Ọjọ́ Ìkẹfà sí ìkéje Oṣù Kẹrin, 2024. David A. Bednar“Ẹ Dúró Jẹ́ẹ́, Kí Ẹ Sì Mọ̀ Pé Èmi Ni Ọlọ́run”Alàgbà Bednar kọ́ni pé nígbàtí a bá “dúró jẹ́,” a lè mọ̀ pé Ọlọ́run ni Baba Ọ̀run àti pé Jésù Krístì ni Olùgbàlà wa. Massimo De FeoDìde! Ó Npè Ọ́Alàgbà De Feo kọ́ni pé àwọn ìbùkún nwá nígbàtí a bá dúró ní ìfojúsùn lórí Jésù Krístì, ronúpìwàdà léraléra, tí a sì fi àyè gba arawa láti ní ìtọ́sọ́nà nípa ohùn Olúwa. Brent H. NielsonÀkọsílẹ̀ nípa Ohun Tí Mo Ti Rí àti Ti Mo Ti Gbọ́Alàgbà Nielson ṣe àpejúwe ìdàgbàsókè Ìjọ tí ó ti rí ní gbogbo àgbáyé. Jose L. AlonsoJésù Krístì ní Ààrin Gbùngbun Ìgbésí Ayé WaAlàgbà Alonso jẹ́ ẹ̀rí pé bí a ti nfi Jésù Krístì sí áàrin gbùngbun ìgbésí ayé wa, a ó rí ìrètí, okun, àti ìwòsàn. Gerrit W. GongOhun Gbogbo fún Rere WaAlàgbà Gong fúnni ní ìdánilójú pé nínú ètò Baba wa Ọ̀run, àní àwọn àjálù àti ìṣòro àdánwò lè jẹ́ fún rere wa. Michael T. NelsonNí Àtìlẹhìn àwọn Ìran Tó NdìdeArákùnrin Nelson kọ́ni pé ìbáṣepọ̀ tí a ní pẹ̀lú àwọn ọ̀dọ́ lè nípa lórí wọn láti ṣe àwọn yíyàn tó dára jù lọ. Quentin L. CookJẹ́ Ọ̀kan pẹ̀lú KrístìAlàgbà Cook kọ́ni pé a níláti tiraka láti mú àwọn míràn wọ inú agbo jíjẹ́ òkannáà wa, pé a wà ní ìrẹ́pọ̀ nípa ìgbàgbọ́ wa nínú Jésù Krístì, àti pé àkójá wíwà nínú ni láti jẹ́ ọ̀kan pẹ̀lú Krístì. Abala Ìrọ̀lẹ́ Sátidé Abala Ìrọ̀lẹ́ SátidéAbala Ìrọ̀lẹ́ Sátidé ti Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Ọlọ́dọdún Ìkẹrìnléláàdọ́wàá ti Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn tí a ṣe ní Ọjọ́ Ìkẹfà sí ìkéje Oṣù Kẹrin, 2024. Shayne M. BowenÀwọn Iṣẹ́ Ìyanu, Àwọn Angẹ́lì, àti Agbára Oyè-àlùfáàAlàgbà Bowen kọ́ni pé àwọn iṣẹ́ ìyanu kò tí ì dáwọ́dúró, àwọn angẹ́lì wà láarín wa, àti pé àwọn ọ̀run ṣí sílẹ̀. Steven R. BangerterTí A Ti Yàn Tẹ́lẹ̀ Láti SìnAlàgbà Bangerter kọ́ awọn ọ̀dọ́ pé a ti yàn wọ́n ṣaájú láti mú awọn iṣẹ́ kan pàtó ṣe ni ayé yí ati pé Ọlọ́run le fi ìwọ̀nyí hàn sí wọn bí wọ́n ti nlépa láti mọ̀ Ọ́ ati láti ṣe ìfẹ́ Rẹ̀. Andrea Muñoz SpannausJíjẹ́ Olõtọ́ dé ÒpinArábìnrin Spannaus kọ́ àwọn ọ̀nà mẹ́fà tí a lè fi múra sílẹ̀ láti dojúkọ ayé kí a sì jẹ́ olotọ dé òpin. Matthew L. CarpenterÈso Tí Ó Ṣẹ́ kùAlàgbà Carpenter kọ́ni nípa májẹ̀mú titun ati ti àìlópin ti ìgbeyàwó àti àwọn ìbùkún ayérayé tí ó mú wá. Dieter F. UchtdorfAyọ̀ Gígajù KanAlàgbà Uchtdorf kọ́ni pé a lè ní ìrírí ayọ̀ gígajù bí a ti nsúnmọ́ tòsí Ọlọ́run, ní ìtiraka láti tẹ̀lé Jésù Krísti, kí a sì wá láti mú ayọ̀ wá fún àwọn wọnnì ní àyíká wa. Abala Òwúrọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi Abala Òwúrọ̀ Ọjọ́ ÌsinmiAbala Òwúrọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi ti Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Ọlọ́dọdún Ìkẹrìnléláàdọ́wàá ti Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn tí a ṣe ní Ọjọ́ Ìkẹfà sí ìkéje Oṣù Kẹrin, 2024. Ronald A. RasbandÀwọn Ọ̀rọ̀ Ṣe PàtàkìAlàgbà Rasband kọ́ni pé àwọn ọ̀rọ̀ Olúwa, ọ̀rọ̀ àwọn wòlíì, àti pé àwọn ọ̀rọ̀ ti ara wa ṣe pàtàkì àti pé sísọ pé “Ẹ Ṣé,” “Mo ní ìkáàánú,” àti “Mo fẹ́ràn yín” lè ràn wá lọ́wọ́ láti fi ìkàsí fún àwọn ẹlòmíràn hàn. Susan H. PorterGbàdúrà, Ó Wà Níbẹ̀Ààrẹ Porter kọ́ àwọn ọmọdé nípa gbígbàdúrà láti mọ̀ pé Baba Ọ̀run wà níbẹ̀, gbígbàdúrà làti dàgbà láti dabí Òun, àti gbígbàdúrà láti fi ìfẹ́ Rẹ̀ hàn sí àwọn ẹlòmíràn. Dale G. RenlundẸ̀kọ́ Alágbára, Agbo Ìwàrere ti KrístìAlàgbà Renlund kọ́ni pé gbígbá ẹ̀kọ́ Krístì mọ́ra kìí ṣe ìṣẹ̀lẹ̀ ìgbà kan lásán ṣùgbọ́n ètò tó ntẹ̀síwájú. Paul B. PieperNí igbẹ́kẹ̀lé nínú OlúwaAlàgbà Pieper kọ́ni pé a lè fún ìbáṣepọ̀ wa pẹ̀lú Ọlọ́run lókun nìkan bí a ti nyàn láti mú ìgbẹ́kẹ̀lé wa nínú Rẹ̀ jinlẹ̀. Patrick KearonÈrò Ọlọ́run Ni Láti Mú Yín WáléAlàgbà Kearon kọ́ni pé a ṣe ètò Ọlọ́run láti ran àwọn ọmọ Rẹ̀ lọ́wọ́ láti padà sílé sọ́dọ̀ Rẹ̀ kí gbogbo wa lè gba ìyè ayérayé. Brian K. TaylorDi Gbígbémì nínú Ayọ̀ KrístìAlàgbà Taylor kọ́ni ní àwọn ìlànà láti rànwálọ́wọ́ ní ìmọ̀lára àlàáfíà, ìrètí, àti ayọ̀ lákoko àwọn ìdánwò. Dallin H. OaksÀwọn Májẹ̀mú àti àwọn OjúṣeÀàrẹ Oaks kọ́ni nípa pàtàkì dídá àwọn májẹ̀mú pẹ̀lú Ọlọ́run ati awọn ìbùkún tí ó nwá.láti inu pípa awọn májẹ̀mú wọnnì mọ́. Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsinmi Abala Ọ̀sán Ọjọ́ ÌsinmiAbala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsinmi ti Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Ọlọ́dọdún Ìkẹrìnléláàdọ́wàá ti Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn tí a ṣe ní Ọjọ́ Ìkẹfà sí ìkéje Oṣù Kẹrin, 2024. D. Todd ChristoffersonẸ̀rí JésùAlàgbà Christofferson kọ́ni ní ohun tó túmọ̀ sí láti jẹ́ akọni nínú ẹ̀rí Jésù ó sì pè wá láti gbé àwọn ìgbésẹ̀ nísisìyí láti wà ní àárín àwọn wọnnì tí wọ́n jẹ́ akọni. Taylor G. GodoyPè, Máṣe ṢubúAlàgbà Godoy kọ́ni pé bí a bá gbàdúrà sí Baba Ọ̀run, Yíò gbọ́ àwọn àdúrà wa ní ọ̀nà ti araẹni. Gary E. StevensonÌsopọ̀ Àwọn Òfin Nlá MéjìṢíṣe àfiwé àwọn òfin nlá méjì sí àwọn ilé-ìṣọ́ lórí afárá, Alàgbà Stevenson kọ́ni ní pàtàkì fífẹ́ràn Ọlọ́run àti àwọn ẹlòmíràn. Mathias HeldÀtakò nínú Ohun GbogboAlàgbà Held kọ́ pé àtakò ṣe pàtàkì fún ìlọsíwájú ayérayé Neil L. AndersenÀwọn Tẹ́mpìlì, Ilé Olúwa Nkún Ilẹ̀-ayéAlàgbà Andersen jẹ́ ẹ̀rí pé àwọn tẹ́mpìlì yíò pamọ́, dá ààbò bò, àti múra wa sílẹ̀ fún ìpadàbọ̀ Jésù Krístì. Mark L. PaceÓ Jẹ́ Ọgbọ́n ninu Olúwa Pé Kí Àwa Ó Ní Ìwé ti Mọ́mọ́nìÀàrẹ Pace kọ́ni bí ṣíṣe àṣàrò Ìwé ti Mọ́mọ́nì ṣe nmú wa súnmọ́ Jésù Krístì tí ó sì nbùkún wa ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà. Russell M. NelsonẸ Yọ̀ nínú Ẹ̀bùn àwọn Kọ́kọ́rọ́ Oyè-àlùfáàÀàrẹ Nelson kọ́ni bí àwọn kọ́kọ́rọ́ oyè-àlùfáà àti ìjọ́sìn tẹ́mpìlì ṣe lè bùkún ìgbé ayé wa.